Ọyẹ́: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
[[Image:MosqueinAbuja.jpg|thumb|right|300px|Ọyẹ́ ní àyíká [[Abuja National Mosque]] in [[Abuja]]]]
 
'''Ọyẹ́''' jẹ́ àsìkò kan lápá iwọ̀-oòrùn [[Áfíríkà]] tí ó má a ń wáyé láàárín ìparí oṣù kọkànlá sí àárín oṣù kẹta ọdún. Ó jẹ́ àsìkò ẹrùn tàbí ọ̀gbẹlẹ̀ tí ó má a ń fa eruku.<ref name="BHarmattan">{{cite web | url=http://www.britannica.com/science/harmattan | title=Harmattan | publisher=Encyclopædia Britannica | access-date=22 July 2015}}</ref> The name is related to the word ''haramata'' in the [[Twi]] language.<ref>{{cite dictionary |year= 2012 |title =Harmattan |dictionary=Merriam-Webster.com |publisher= [[Merriam-Webster]] |url=http://www.merriam-webster.com/dictionary/Harmattan }}</ref> Ó má a ń jẹ́ àsìkò òtútù, ní àwọn àgbègbè mìíràn ẹ̀wẹ̀, ó má ń jẹ àsìkò oru, èyí máa ń dá lórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ọjọ́ ní irú àgbègbè bẹ́ẹ̀.<ref>''Geographical Review'' (1919): "Knox writes of this wind : The Harmattan is experienced as a wind which blows, especially in the months of December, January, and February, from the NE. and is a hot wind in some localities and a cold wind in others, according to circumstances."</ref>
 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ọyẹ́"