Tunisia: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
No edit summary
Ìlà 66:
'''Tùnísíà''' ({{IPAc-en|US|audio=En-us-Tunisia.ogg|t|uː|ˈ|n|iː|ʒ|ə}} {{respell|two|NEE|zhə}} or {{IPAc-en|UK|tj|uː|ˈ|n|ɪ|z|i|ə}} {{respell|tew|NIZ|iə}}; {{lang-ar|تونس}} ''{{transl|ar|Tūnis}}'' {{IPA-ar|ˈtuːnɪs|pron}}), lonibise bi '''Orile-ede Olómìnira ara Tùnísíà'''<ref group="note">The long name of Tunisia in [[Languages of Tunisia|other languages]] used in the country is:
* {{lang-ber|ⵜⴰⴳⴷⵓⴷⴰ ⵏ ⵜⵓⵏⴻⵙ}} ''{{transl|ber|Tagduda n Tunes}}''
* {{lang-fr|République tunisienne}}</ref> ({{lang-ar|الجمهورية التونسية}} ''{{transl|ar|al-Jumhūriyyah at-Tūnisiyyah}}'' {{IPAc-ar|2|a|l|.|j|u|m|.|h|uu|'|r|i|y|.|y|a|.|t_|a|t|.|t|uu|.|n|i|'|s|i|y|.|y|a}}), ni orile-ede [[North Africa|apaariwajulo]] ni [[Afrika]]. O je orile-ede [[Maghreb]] kan, be si ni o ni bode mo [[AlgeriaÀlgéríà]] ni iwoorun, [[Libya]] ni guusuilaorun, ati [[Mediterranean Sea|Omiokun Mediterraneani]] si ariwa ati ilaorun. Aala re je {{convert|165000|km2|sqmi}}, pelu idiyele alabugbe to je egbegberun 10.4. Oruko re wa lati inu oruko oluilu re [[Tunis]] to budo si ariwa-ilaorun.
 
Tunisia je orile-ede to kerejulo to budo si eba [[Atlas mountains|oke Atlas]]. Guusu orile-ede na je kiki aginju [[Sahara desert|Sahara]], pelu eyi to to je kiki ile olora ati eti okun {{convert|1300|km|mi}}. Awon mejeji ko ipa pataki igba atijo, akoko pelu ilu [[Carthage]] awon [[Punic]], leyin re bi igberiko ile [[Roman Empire|Romu]] ni [[Africa (Roman province)|Africa]], to gbajumo bi "apere onje /bread basket" ile Romu. Leyin re, Tunisia bo so wo awon [[Vandals]] ni orundun 5k LK, awon [[Byzantine Empire|Byzantine]] ni orundun 6k, ati awon [[Arabs|Arabu]] ni orundun 8k. Labe [[Ottoman Empire|Ileobaluaye Ottomani]], Tunisia je mimo bi "Iluoba Tunis/Regency of Tunis". O bo sowo ibiabo [[France|Fransi]] ni 1881. Leyin ominira ni 1956 orile-ede na di "Ileoba Tunisia" leyin ijoba [[Lamine Bey]] ati [[Husainid Dynasty|Iran-oba Husainid]]. Pelu ifilole Orile-ede Olominira ara Tunisia ni July 25, 1957, olori aseolorile-ede [[Habib Bourguiba]] di aare akoko.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Tunisia"