Lateef Adedimeji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 33:
==Ìgbé ayé tí ara ẹni==
Ni ọjọ kejidinlogun oṣù Kejìlá ọdún, 2021, Adedimeji fẹ afesona re , [[Oyebade Adebimpe]] ni ìgbéyàwó tí ọ l'arin rìn.<ref>{{Cite web|url=https://www.bbc.com/pidgin/media-59712969.amp|title=See photos from actor Lateef Adedimeji wedding wit colleague Adebimpe Oyebade|date=18 December 2021}}</ref>
 
 
== Iṣẹ ==
Lateef Adedimeji bẹrẹ sí ní se ere ori itage ni ọdún 2007,o sí bẹrẹ ìjọ pẹlu ,<ref name=":1" /> a gba sí ilé ìwé ìjọ. Lateef Adedimeji jẹ [[Actor]] and [[Screenwriter]]. Lateef Adedimeji o ti farahàn ni orisiirisii èrè ori itage lati ọmọ ọdún mẹdogun sùgbón o bẹrẹ èrè ni ọdún 2007 nígbàtí o fara hàn lori ero amohun maworan Orisun TV. O bẹrẹ èrè ori itage lati ile iwe akọbẹrẹ started a Yàn láti sójú NGO gẹgẹ bí olufihan àrùn kogboogun [[HIV/AIDS]] campaign. Ipá rẹ ní lati sọ nípa àìsàn tí ọ bẹ ninu ìbálòpọ̀ [[human rights]] làti má ṣe àwòrán. Awọn ololufẹ rẹ mọ gẹgẹ bí ẹni tó mú iṣẹ rẹ ní okunkundun. O ti ṣe àfihàn pẹlu oríṣiríṣi awọn àgba òṣèré. Ni ọdún 2016, o gba àmì ẹ̀yẹ [[2016 Best of Nollywood Awards]] fun eléré ti ọ da yangan julọ (Yoruba).<ref>{{Cite web|url=https://quopedia.blogspot.com/2017/11/lateef-adedimeji.html |title=Lateef Adedimeji Biography|website=quopedia.blogspot.com }}</ref> ni ọdún 2015,a ka mo ará awọn ti ọ yẹ ki o gba àmì ẹ̀yẹ [[City People Entertainment Awards]] fún eléré ọdún 2015. Lateef jẹ ẹni tí a má n gbe Gbagi fún [[Odunlade Adekola]] nitori won jọ ará wọn àti ìwùwà. O ni anfààní lati ṣiṣẹ pẹlú [[UNICEF]] nítori ìwé kíkọ .<ref>{{Cite web |url=https://theinfopro.com.ng/lateef-adedimeji-biography-net-worth-wikipedia/|title=Lateef Adedimeji Biography and Network 2019 |website=theinfopro.com }}</ref> a fún ní àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí ojú nollywood [[Nollywood]] male<ref>{{Cite web|title=Premium Times – Nigeria leading newspaper for news, investigations|url=https://premiumtimesng.com/|access-date=20 November 2021|language=en-GB}}</ref>during the ENigeria Newspaper Night of Honour on 30 October 2021.
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==