Ọdún Iléyá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àtúnṣe kéré àti ìfi àmì si
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 16:
|date2010=November 16 to November 19 (calculated)
}}
'''Ọdún Iléyá''' ({{lang-ar|عيد الأضحى}} ''‘Īdu l-’Aḍḥā'' tabi '''Aïd el-Kabir''') "OdunỌdún IdupeÌdúpẹ́-OoreỌòrẹ" jejẹ́ ojoọjọ́ isinmiìsinmi patakipàtàkì ninunínú esinẹsìn IslamÌsìlàámù ti awonàwọn [[Muslim|MusulumiMùsùlùmí]] unjoyoṣe kakiriàjọyọ̀ aye latikáàkiri serantiàgbáyé ifeláti ṣerántí àmì kàn tí wọ́n ní ìfẹ sí tí ó ń jẹ́ Ànọ́bì Ìbùrọ̀hìmù ([[Abraham|Abraham)]] ([[Islamic view of Abraham|Ibrahim]]).<ref>[http://www3.kumc.edu/diversity/ethnic_relig/eid-al-adha.html Diversity Calendar: Eid al-Adha] University of Kansas Medical Center</ref>
 
Oríṣiríṣi àlàyé ló wà fún ọdún yìi, lára àwọn àlàyé náà ni:
Ni odun 1991, Sheikh Dr. Abu-Abdullah Adelabu se alaiye nipa Ọdún Iléyá ni ori ero-sorosoro Radio Abuja wipe Odu Ileya je ajodun Ifi-emi-imoore-han Olohun ni ikose Ibrahim ti o fi emi-imoore han nigbati o fe fi omo re Ishmael sile fun ifi emi-imoorehan si Olorun ti O se adehun fun oun Ibrahim wipe oun yio bi omo ninu ogbo.
 
Ninu waasi Sheikh naa ti i se omobibi orile ede Nigeria, a gbo lori eto ajodun odun ti osise agba Musulumi Alhaji Guranga se olootu ati olugbalejo lori ero-sorosoro naa wipe, fifi omo bibi Ibrahim sile ko i se riru ebo. Sheikh Adelabu ti awon omo lehin re nse igbejade EsinIslam.Com lati pase ile-eko Islam Awqaf Africa ni Ilu London se alaiye ni ede Yoruba lori ero Radio Abuja wipe idanwo ni Olohun se fun awon Ibrahim lati se ifirinle jije oluse-rere, olotito, olododo ati olumo-oore.
 
Onimimo Yoruba yi se itumo awon ese-oro ninu Quran bayi wipe<ref>[http://www.esinislam.com/Quran_And_Hadith/Arabic_Engilsh_Quran/Arabic_English_Quran_Surah_37.htm Awon Aaya yi ninu Quran se ekunrere ni Surah As-Safaat 37:100-111</ref>:
 
Ní ọdún 1991, Sheikh Dr. Abu-Abdullah Adélabú ṣe àlàyé nípa Ọdún Iléyá ní orí Ẹ̀rọ-sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ Rẹ́díò Abùjá wípé Ọdún Iléyá jẹ́ àjọ̀dún ìfi-ẹ̀mí-ìmọorè-hàn, Ọlọ́hun ní kí Ibrahim ó ṣe láti fi ẹ̀mí-ìmọ́orè hàn èyí tí ó sí fí ọmọ rẹ̀ Ishmael sílè fún ìfi ẹ̀mí-ìmọ́orè hàn sí Ọlọ́run tí ó ṣe àdéhùn fún pé bí oun Ibrahim bá bímọ nínú ogbó pé òun yóò fí ọmọ náà jọ́sín fún Ọlọ́run.
"Oun (Ibrahim) si so wipe: "Olohun mi o! Fun mi ni omo rere" Bee naa sini Awa (Olohun Oba-Aaso) si fun ni irohin ayo wipe oun (Ibrahim) yio ri Omo kunrin (Ishmael) bi. Nitori idi eyi, nigbati oun (omo okunrin keke re naa, Ishmael) dagba de bi ti o le rin kaakiri (fun ijihin-rere) pelu Ibrahim, oun (Ibrahim) si wi fun wipe: Iwo omo mi (Ishmael) o! A ti fi han mi l'ju ran wipe mo fi o se idupe oore (niti fifeni sile fun idupe l'owo olohun), abi iwo ko ri bi nkan tiri bi - kin ero tire?! Oun (Ishmael) si da (baba re Ibrahim) lohun wipe: "Iwo baba mi o! Se gege bi A ti se pa iwo l'ase lati se, Inshâ' Allâh (Ni ti Ogo-Olohun) iwo yio si mo bi mo ti je ninu awon As-Sâbirin (Awon Olufarada ninu suuru ati oun ti o jomo bee gbogbo).
 
Nínú wàásí Sheikh náà tí í ṣe ọmọ-bibi orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gbo lórí ètò àjọ̀dún ọdún tí òṣìṣẹ́ àgbà Mùsùlùmí Àlàájíaji Gúrúrángà ṣe olóòtú àti olú-gbàlẹjọ̀ lórí ẹ̀rọ-sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ náà wípé, fífi ọmọ bíbí Ibrahim sílè kì ì ṣe rírú ẹbọ. Sheikh Adélabú tí àwọn ọmọ lẹ́hìn rẹ̀ ń ṣe ìgbéjáde Ẹ̀ṣín isilaamu.Com láti pàṣẹ ilé-èkó Ìsìlàámù Awqaf Africa ní Ìlú London ṣé àlàyé ní èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ Rédíò Abùjá wípé ìdánwò ní Ọlọ́hun ṣe fún Ànọ́bì ibrahim láti ṣe Ìfi- rinlẹ̀ jíjẹ olúsìn-rere, olótìitọ̀, olódodo àti olumọ̀- oore.
Lehin eyi, ti awon mejeeji si ti gba fun Olohun won Allah ti nwon si se ijuwo-juse sile fun Ife Olohun), ti oun (Ibrahim) si ti te ori re (Ishamel) lo sile (ni aaye iteba si iwaju);
 
OnimimoOnímímọ̀ YorubaYorùbá yiyíì seṣe itumoìtumò awonàwọn eseẹsẹ-oro ninuọ̀rọ̀ Qurannínú bayikúránì báyìí wípé wipe<ref>[http://www.esinislam.com/Quran_And_Hadith/Arabic_Engilsh_Quran/Arabic_English_Quran_Surah_37.htm Awon Aaya yi ninu Quran se ekunrere ni Surah As-Safaat 37:100-111</ref>:
"Bayi naa ni Awa si pe oun: "Iwo Ibrahim o!"
 
"Òun (Ibrahim) sí sọ wípé: "Ọlọ́hun mí ó! Fún mí ní ọmọ rere" Bẹ́ẹ̀ náà síní Àwa (Ọlọ́hun Ọba-Áaso) sí fún ní ìròyìn ayọ̀ wípé òun (Ibrahim) yì ó rí Ọmọkùnrin (Ishmael) bí. Nítorí ìdí èyí, nígbà tí òun (ọmọ ọkunrin kékeré náà, Ishmael) dàgbà dé bí tí ó lè rìn káàkiri (fún ìjíhìn-rere) pẹ̀lú Ibrahim, òun (Ibrahim) sí wí fún wípé: Ìwọ ọmọ mí (Ishmael) ó! A ti fi hàn mí l'ójú rán wípé mo fí ọ ṣe ìdúpẹ́ oore (ní ti fífẹni sílẹ̀ fún ìdúpẹ́ l'ọ́wọ Ọlọ́hun), àbí ìwọ kò rí bí nkán ti rí bí - kíni èrò tìre?! Òun (Ishmael) sí da (bàba rẹ̀ Ibrahim) lóhùn wípé: "Ìwọ bàba mi ó! Ṣe gẹ́gẹ́ bí A ti ṣe pa ìwọ l'ásẹ láti ṣe, Inshâ' Allâh (Ní ti Ògo-Ọlọ́hun) ìwọ yì ó sí mo bí mo ti jẹ́ nínú àwọn As-Sabirin (Àwọn Olufàradà nínú sùúrù àti òun tí ó jọmọ́ bẹ́ẹ̀ gbogbo).
"Iwo (Ibrahin) ti se gege bi A ti fi han o (ni ojuran) ni otito ati ni ododo! Bayi naa si ni Awa se ma n san esan fun (gbogbo awon) Muhsinûn (oluserere lotito ati lododo) - Sheikh Adelabu se itoka si Ese-Oro Olohun ninu Quran Ori 2:112)."
 
Lẹ́hìn èyí, tí àwọn méjèèjì sí ti gbà fún Ọlọ́hun wọn Allah tí wọ́n sì ṣe ijúwọ̀-jusẹ̀ sílè fún Ìfẹ Ọlọ́hun), tí òun (Ibrahim) sí tí tẹ́ orí ẹ́e (Ishamel) lọ sílẹ̀ (ní ààyè itébà sí iwájú);
Lai ko se aniani, idanwo nla ti o fi oju han gbangba ni eleyi je. Nitori idi eyi ni A wa fi se iropo (gege bi irapada) omo (Ishamael) ti oun (Ibrahim) naa pelu aguntan kan bolojo (lati fi dipo ni sise idupe oore lati Odo Olohun)
 
"Báyìí náà ní Àwa sí pé òun: "Ìwọ Ibrahim o!"
"Bayi naa si ni A wa je ki o wa nile fun un (Ibrahin) iranti rere ti o si di manigbagbe fun ati laarin awon aromodomo ti oun bo lehin titi lailai And We left for him (a goodly remembrance) among generations (to come) in later times."
 
"Ìwọọ (Ibrahin) tí ṣe gẹ́gẹ́ bí A ti fi hàn ó (ní ojúran) ní òtítọ àti ní òdodo! Báyìí náà sì ní Àwa ṣe má ń san ẹ̀san fún (gbogbo àwọn) Múhsínùn (olùṣe rere lótitọ àti l'ódodo) - Sheikh Adélabú ṣe ìtọka sí Ẹsẹ Ọrọ Ọlọ́hun nínú kúránì Orí 2:112)."
 
Láì kọ́ ṣe àníàní, ìdánwò nlá tí ó fi ojú hàn gbángba ní eléyìí jẹ́. Nítorí ìdí èyí ní À wa fi ṣe ìrópò (gẹ́gẹ́ bí ìràpadà) ọmọ (Ishamael) tí òun (Ibrahim) náà pẹ̀lú àgùntàn kàn bọ̀lọ̀jọ̀ (láti fi dípò ní ṣíṣe ìdúpẹ́ òòrè láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́hun)
 
"Báyìí náà sì ní À wa jẹ́ kí ó wá nílé fún un (Ibrahin) ìrántí rere tí ó sì di mánìgbàgbé fun àti láàrín àwọn àrọ́mọdọ́mọ tí òun bọ̀ lẹ́hìn Títí Láíláí.
 
{
 
(
 
"SalâmunSàlámùn 'alaa Ibrâhim (Abraham) i.e. IkeÌkẹ́ atiàti igeìgẹ̀ (OlohunỌlọ́hun) ni funfún Ibrahim (Abraham)"}<ref>[http://www.esinislam.com/MediaYoruba/index.php Fun ekunrere alaiye yi ni Ede Yoruba, e wo EsinIslam.Com</ref>.
 
"Salâmun 'alaa Ibrâhim (Abraham) i.e. Ike ati ige (Olohun) ni fun Ibrahim (Abraham)"<ref>[http://www.esinislam.com/MediaYoruba/index.php Fun ekunrere alaiye yi ni Ede Yoruba, e wo EsinIslam.Com</ref>.