Ìpínlẹ̀ Delta: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe lórí ẹ̀rọ alágbéká Android app edit
No edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe lórí ẹ̀rọ alágbéká Android app edit
Ìlà 27:
|}
'''Ipinle Delta''' je ipinle kan nini awon [[Awon Ipinle Naijiria|Ipinle]] ni orile-ede [[Naijiria]]. Ìpínlè Delta wà ní apa Guusu [[Nàìjíríà]]. Adá Ìpínlè Delta kalè ní ojo ketadinlogbon, osu kejo, odun 1991(27, August 1991) ní abe isejoba Gen. Ibrahim Babangida <ref name="Nigeriagalleria 1991">{{cite web | title=Brief History of Delta State:: Nigeria Information & Guide | website=Nigeriagalleria | date=1991-08-27 | url=https://www.nigeriagalleria.com/Nigeria/States_Nigeria/Delta/Brief-History-of-Delta-State.html | access-date=2022-03-26}}</ref>. Olú-ìlú Ìpínlè Delta ní Asaba bí otile jepe ìlú Warri ìkan aje/oja kale sí jù. Àwon èyà tí opoju ní Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri <ref name="FamilySearch Wiki 2020">{{cite web | title=Delta State, Nigeria Genealogy | website=FamilySearch Wiki | date=2020-04-11 | url=https://www.familysearch.org/en/wiki/Delta_State,_Nigeria_Genealogy | access-date=2022-03-26}}</ref>. Ìpinlè Delta ní Ìjoba Agbegbe Ibile marundinlogbon(25) <ref name="Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria">{{cite web | title=Local Government Areas in Delta State | website=Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria | url=https://www.manpower.com.ng/places/lgas-in-state/11/delta-state | access-date=2022-03-26}}</ref>
==Awon Ìjoba Agbegbe Ìbílè ti Delta==
• Aniocha North
• Aniocha South
• Bomadi
• Burutu
• Ethiope South
• Ethiope east
• Ika North East
• Ika South
• Isoko North
• Isoko South
• Ndokwa east
• Ndokwa west
• Okpe
• Oshimili North
• Oshimili South
• Patani
• Sapele
• Udu
• Ughelli North
• Ughelli South
• Ukwuani
• Uvwie
• Warri North
• Warri South
• Warri South West
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}