Orílẹ̀ èdè America: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ìmúkúrò àtúnyẹ̀wò 549921 ti 112.223.43.43 (ọ̀rọ̀)
Ìlà 82:
 
== Orisun itumo ==
Ni 1507, [[Martin Waldseemüller]] [[cartography|ayamaapu]] ara Jemani pese maapu lori ibi to ti pe oruko awon ile ti won wa ni [[Western Hemisphere|Ibiilaji Apaiwoorun]] bi [[Americas|"Amerika"]] lati inu oruko oluwakiriri ati ayamaapu ara Italia [[Amerigo Vespucci]].<ref>{{cite web|url=http://www.usatoday.com/news/nation/2007-04-24-america-turns-500_N.htm?csp=34|title=Cartographer Put 'America' on the Map 500 years Ago|work=USA Today|date=2007-04-24|accessdate=2008-11-30}}</ref> Awon ibiamusin Britani tele metala koko lo oruko orile-ede yi ninu [[United States Declaration of Independence|Ifilole Ilominira]], bi "Ifilole alafenuko awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("unanimous Declaration of the thirteen united States of America") to je gbigba mu latowo "Awon Asoju awon Ipinle aparapo ile Amerika" ("Representatives of the united States of America") ni ojo 4 Osu Keje, 1776.<ref>{{cite web|url=http://www.archives.gov/exhibits/charters/charters.html|title=The Charters of Freedom|publisher=National Archives|accessdate=2007-06-20}}</ref> Ni ojo 15 Osu Kokanla, 1777, Ipejo Olorile Keji gba awon Ese-oro Ikorapapo, to so pe, "Oruko Ijekorapapo yi yio je 'Awon Ipinle Aparapo ile Amerika'" ("The Stile of this Confederacy shall be 'The United States of America.'") Awon iwe adehun lari Fransi ati Amerika odun 1778 lo "Awon Ipinle Aparapo ile Ariwa Amerika ("United States of North America"), [https://ariamarket.kr/ sugbon] lati ojo 11 Osu [http://inbor.kr/ Keje], 1778, "Awon Ipinle Aparapo ile Amerika" ("United States of America") lo je lilo lori awon owo fun pasiparo, latigbana [http://sjta.kr/ eyi] lo ti je oruko onibise re.<ref>{{cite web|author=McClure, James|url=http://www.ydr.com/ci_9569289|title=A Primer: The 'First Capital' Debate|publisher=YDR.com|date=2008-06-12|accessdate=2010-07-26}}</ref>
 
Ni [https://kiria.kr/ ede] Yoruba "Orile-ede Amerika" tabi "Amerika" lasan loruko to wopo. A tun le lo lo "U.S." tabi "USA".
 
Awon araalu awon Ipinle Aparapo ile Amerika la mo bi awon ara Amerika.<ref>Wilson, Kenneth G. (1993). ''The Columbia Guide to Standard American English''. New York: Columbia University Press, pp. 27–28. ISBN 0-231-06989-8.</ref>