Peter Obi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
kNo edit summary
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 27:
A bí Peter Obi si [[Onitsha]] ni 19 July, 1961. O lo [[ilé-ìwé sekondiri]] rè ní ilé-ìwé Christ The King College ni [[Onitsha|Onitsha.]]<ref name="Kolesnik 2018">{{cite web | last=Kolesnik | first=Kay | title=Peter Obi: early years, education, career and family | website=Legit.ng - Nigeria news. | date=2018-09-03 | url=https://www.legit.ng/1189429-peter-obis-biography-career.html | access-date=2022-06-29}}</ref> Ni odun 1980, a gbàá sile ìwé [[Yunifásitì ti Nàìjíríà]], [[Nsukka]], ósì gba àmì-èye nínú ìmò philosophy ní odun 1984.<ref name="Vanguard News 2018">{{cite web | title=Peter Obi: A complete profile | website=Vanguard News | date=2018-10-13 | url=https://www.vanguardngr.com/2018/10/peter-obi-a-complete-profile/ | access-date=2022-06-29}}</ref> O padà lo ilé-ìwé onisowo ti [[Èkó]]
==Ki o to wo oselu==
Peter Obi je [[onisowo okunrin]] koto dipe ó wo [[Òṣèlú|oselu,]]<ref name="A 2021">{{cite web | last=A | first=Olumide | website=Kemi Filani News | date=2021-10-08 | url=https://www.kemifilani.ng/breaking-news/peter-obis-biography-daughter-wife-net-worth | access-date=2022-06-29}}</ref> Obi sope a bi oun sínú idile olutaja, òun náà si ún taja koto dipé obere sí ún sisé ní àwon [[ilé-isé]], ó di ipo adari mu ní àwon ilé-isé bi: [[Next International Nigeria Ltd]], [[Chairman and Director of Guardian Express Mortgage Bank Ltd]], [[Guardian Express Bank Plc]], [[Future View Securities Ltd]], [[Paymaster Nigeria Ltd]], [[Chams Nigeria Ltd]], [[Data Corp Ltd and Card Centre Ltd]]., òun ni èni to kéré jù ninú àwon to ti je alaga ilé [[ifowopamo Fidelity]] ri.<ref name="The Sun Nigeria 2016">{{cite web | title=Managing recession: The Duke, Obi examples | website=The Sun Nigeria | date=2016-10-11 | url=https://www.sunnewsonline.com/managing-recession-the-duke-obi-examples/ | access-date=2022-06-29}}</ref>
==Òsèlú==
Ni odun 2003, Obi díje fún ipò Gomina ìpínlè Anambra sùgbón o fìdíremi fún alatako rè, Chris Ngige, èni tí o jé oludije lábé egbé oselu People's Democratic Party(PDP), Obi gbé oro náà lo ilé ejó Court of appeal, nibi ti wón ti rojo oro náà fun odun meta koto dipe wón yo Chris Ngige nípò lati gbe Obi wolé ní osu Keta, odun 2006,, ni osu Kokanla odun 2006, àwon omo egbé ìgbìmò asofin ti ìpínlè Anambra yo Obi nípò gomina, wón si fi igba kejì rè, Virginia Etiaba sípò Gomina, èyi mú kí Virginia jé Gomina obinrin àkókò ni orílè-èdè Nàìjíríà.<ref name="The Mail & Guardian 2006">{{cite web | title=Nigeria's Anambra replaces impeached governor | website=The Mail & Guardian | date=2006-11-03 | url=https://mg.co.za/article/2006-11-03-nigerias-anambra-replaces-impeached-governor/ | access-date=2022-06-29}}</ref>Ilé ejó Court of Appeal tún da Peter Obi padà sipo Gomina, Virginia da agbara padà fún Peter Obi léyìn idajo ile ejó.<ref name="Reporters 2007">{{cite web | last=Reporters | first=Sahara | title=Peter Obi wins, he takes over! | website=Sahara Reporters | date=2007-02-08 | url=https://saharareporters.com/2007/02/08/peter-obi-wins-he-takes-over | access-date=2022-06-29}}</ref>
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Peter_Obi"