Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Fixed a typo
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
kNo edit summary
Ìlà 75:
}}
 
'''Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun''' jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn [[Awon Ipinle Naijiria|Ìpínlẹ̀]] ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun jẹ́ [[States of Nigeria|Ìpínlẹ̀]] tí ó wà ní àárín gbùngbùn apá Ìwọ̀-Oòrùn Gúúsù orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Olú-ìlú rẹ̀ wà ní Ìlú [[Òṣogbo]]. Ó ní ibodè ní àríwá mọ́ [[Ipinle Kwara]], ní ìlà-oòrùn díẹ̀ mọ́ [[Ipinle Ekiti]] àti díẹ̀ mọ́ [[Ipinle Ondo]], ní gúúsù mọ́ [[Ipinle Ogun]] àti ní ìwọ̀oòrùn mọ́ [[Ipinle Oyo]]. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ni Gómìnà [[Gboyega Oyetola]] .<ref name="Premium Times Nigeria 2019">{{cite web | title=Supreme Court affirms Gboyega Oyetola's election as Osun Governor | website=Premium Times Nigeria | date=2019-07-05 | url=https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/338994-breaking-supreme-court-affirms-gboyega-oyetolas-election-as-osun-governor.html | access-date=2019-09-18}}</ref> Wọ́n dìbò yàn-án wọlé ní 2018.<ref name="BBC News Pidgin 2019">{{cite web | title=Appeal Court say Oyetola win Osun election | website=BBC News Pidgin | date=2019-05-09 | url=https://www.bbc.com/pidgin/tori-48211765 | access-date=2019-09-18}}</ref> Ọsun ní ibi tí ọ̀pọ̀ àwọn ibi mèremère tó gbajúmọ̀ wà. Ọgbà [[Obafemi Awolowo University|Yunifasiti Obafemi Awolowo]] to wa ni [[Ile-Ife|Ile-Ifẹ]], ibi tó ṣe pàtàkì nínú àṣà Yorùbá. Àwọn ìlú tóṣe pàtàkì ní ìpínlẹ̀ Ọ̀sun tún ni [[Oke-Ila|Oke-Ila Orangun]], [[Ila, Nigeria|Ila Orangun]], [[Ede, Nigeria|Ede]], [[Iwo, Nigeria|Iwo]], [[Ejigbo]], [[Esa-Oke]] àti [[Ilesa]].A da ipinle osun sile ni 27/08/1991,
 
==Itan==