Ìpínlẹ̀ Ògùn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
kNo edit summary
Ìlà 71:
| footnotes =
}}
'''Ìpínlẹ̀ Ògùn''' jẹ ọ̀kan lára àwọn [[Ipinle Nàìjíríà|Ìpínlẹ̀]] mẹ́rìndínlógójì tí ó wà ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. Wọ́n da Ìpínlẹ̀ Ògùn sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kejì, ọdún [[1976]]. Ìpínlẹ̀ Ògùn fi ẹ̀gbẹ́ kan ẹ̀gbẹ́ pẹ̀lú [[Ìpínlẹ̀ Èkó]] lápá gúúsù, [[Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́]] àti [[Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]] lápá àríwá, [[Ìpínlẹ̀ Òndó]] àti [[Benin|Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Benin]] lápá ìwọ̀-oòrùn. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ni Ọmọọba [[Dapo Abiodun]] tí wọ́n dìbò yàn-án wọlé lọ́dún 2019. [[Abẹ́òkúta]] ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn àti ìlú tí ó ní ọ̀pọ̀ olùgbé jùlọ ni ìpínlẹ̀ náà. Méjì lára àwọn ìlú míràn tí ó ṣe pàtàkì ni Ìpínlẹ̀ Ògùn ni [[Ìjẹ̀bú-Òde]], olú-ìlú ọba aládé tí [[Ìjẹ̀bú Kingdom]] fún ìgbà kàn rí àti [[Sagamu|Sagamu,]] ìlú tí ńṣe aṣáájú níbi ká gbin obì lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ijoba ibile Ado odo ota je okan pataki lara awon ijoba ibile ni ipinle ogun to n se agbateru oro aje to munadoko.
 
== Àwọn ènìyàn tó ti jáde ní ìpínlẹ̀ Ògùn ==