Ìpínlẹ̀ Bayelsa: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Atunkọ arokọ
Ìlà 26:
|colspan="2" valign="top"|NG-BY
|}
 
'''Ipinle Bayelsa''' jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn [[Àwọn Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà|Ìpínlẹ̀ 36]] tó wà ní orílè-èdè [[Nàìjíríà]]. Wọ́n dá ìpínlẹ̀ Bayelsa sílẹ̀ ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1996. Ọ̀gbẹ́ni [[Seriake Henry Dickson]] tí ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ni Gómìnà [[ìpínlẹ̀ Bayelsa]] tí ó ń palẹ̀mọ́ láti kúrò ti Ọ̀gbẹ́ni [[David Lyon]] tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn lábẹ́ ẹgbẹ́ àsíyá [[All Progressives Congress]] yóò gba ọ̀pá àṣẹ láti di Gómìnà ìpínlẹ̀ náà.<ref name="James 2019">{{cite web | last=James | first=Akam | title=Bayelsa Governor-elect, David Lyon sets up 59-member transition committee - Daily Post Nigeria | website=Daily Post Nigeria | date=2019-11-28 | url=https://dailypost.ng/2019/11/28/bayelsa-governor-elect-david-lyon-sets-up-59-member-transition-committee/ | access-date=2019-11-30}}</ref> <ref name="Punch Newspapers 2015">{{cite web | title=APC dislodges PDP in Bayelsa, wins governorship election | website=Punch Newspapers | date=2015-12-15 | url=https://punchng.com/apc-dislodges-pdp-in-bayelsa-wins-governorship-election/ | access-date=2019-11-30}}</ref> <ref name="PropertyPro Insider 2017">{{cite web | title=History of Bayelsa State | website=PropertyPro Insider | date=2017-07-14 | url=https://www.propertypro.ng/blog/history-of-bayelsa-state/ | access-date=2019-11-30}}</ref> [[Yenagoa]] ni Olú-ìlú ìpínlẹ̀ Bayelsa.<ref name="Guide to Nigeria tourism, local culture & investments 2011">{{cite web | title=Bayelsa State History, Tourist Attractions, Hotels & Travel Information | website=Guide to Nigeria tourism, local culture & investments | date=2011-03-13 | url=https://www.cometonigeria.com/region/south-south/bayelsa-state/ | access-date=2019-11-30}}</ref>
 
'''Ìpínlẹ̀''' '''Bayelsa''' jẹ́ ìpínlẹ̀ kan láàárín [[Àwọn Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà|àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì]] ní agbègbè Gúúsù-Gúúsù ní orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]]. tí ó wà ní gbùnnùgbúnnù agbègbè [[:en:Niger_Delta|Niger Delta]].<ref>{{Cite web|title=Yenagoa {{!}} Location, Facts, & Population|url=https://www.britannica.com/place/Yenagoa|access-date=2021-09-11|website=Encyclopedia Britannica|language=en}}</ref><ref name=":1">{{Cite web|title=Bayelsa – History & Culture – Bayelsa State Government|url=https://bayelsastate.gov.ng/our-history/|access-date=2021-09-11|language=en-US}}</ref> Wọ́n dá Ìpínlẹ̀ [[:en:Bayelsa_United_F.C.|Bayelsa]]<ref>{{Cite web|title=Bayelsa State|url=https://www.bbc.com/pidgin/topics/c5qvpq9d50nt|access-date=2022-03-06|website=BBC News Pidgin}}</ref> sílẹ̀ ní ọdún 1996 wọ́n sì dá ààyè rẹ̀ yọ kúrò nínú Ìpínlẹ̀ [[:en:Rivers_State|Rivers]],<ref name="Rivers state Archives">{{Cite web|title=Rivers state Archives|url=https://guardian.ng/tag/rivers-state/|access-date=2022-03-06|website=The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News|language=en-US}}</ref> ní èyí tí ó mu jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ìpínlẹ̀ titun ní orílẹ̀ èdè. [[:en:Yenagoa|Yenagoa]] ni olú-ìlú rẹ̀. Ìpínlẹ̀ Bayelsa àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbègbè rẹ̀ bọ́sí ibi ẹ̀kun-omi tí ó léwu jùlọ, tí ó ṣeéṣe kí ó máa sẹlẹ̀ lọ́dọọdún. Ó pín ààlà pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ [[:en:Rivers_State|Rivers]]<ref name="Rivers state Archives" /> sí ìlà-oòrùn àti Ìpínlẹ̀ [[:en:Delta_State|Delta]] sí ìlà-oòrùn, pelu àwọn omi ti [[:en:Atlantic_Ocean|Atlantic Ocean]]<ref>{{Cite web|date=2019-03-18|title=The Atlantic Ocean—facts and information|url=https://www.nationalgeographic.com/environment/article/atlantic-ocean|access-date=2022-03-05|website=Environment|language=en}}</ref> ti ó jẹ gàba lórí àwọn ààlà gúúsù rẹ̀.<ref name=":1" /> Ó ní agbègbè tó tó 10, 773 km2.<ref>{{Citation|title=Citation Needed|date=2017-04-03|url=http://dx.doi.org/10.14325/mississippi/9781496811325.003.0047|work=Retcon Game|publisher=University Press of Mississippi|access-date=2022-09-01}}</ref> Ìpínlẹ̀ náà ṣàkónú agbègbè ìjọba ìbílè mẹ́jọ. Àwọn sì [[:en:Ekeremor|Ekeremor]], [[:en:Kolokuma/Opokuma|Kolokuma/Opokuma]], [[:en:Yenagoa|Yenagoa]], [[:en:Nembe|Nembe]], [[:en:Ogbia|Ogbia]], [[:en:Sagbama|Sagbama]], [[:en:Brass,_Nigeria|Brass]] àti Gúúsù-Ijaw.<ref name=":1" /> Ìpínlẹ̀ náà pín ààlà pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Rivers,<ref>{{Cite web|title=Your-Title-Here|url=https://www.riversstate.gov.ng/|access-date=2022-03-06|website=www.riversstate.gov.ng|language=en}}</ref> ní èyí tí oh jẹ́ apákan tẹ́lẹ̀rí, àti Ìpínlẹ̀ Delta.<ref name=":0">{{Cite web|url=http://www.ngex.com/nigeria/places/states/bayelsa.htm|title=Learn About Bayelsa State, Nigeria {{!}} People, Local Government and Business Opportunities in Bayelsa|website=Overview of Nigeria {{!}}NgEX|language=en|access-date=2018-07-29}}</ref><ref name=":2">{{Citation|title=Référence rapide des codes de la CITE-P et de la CITE-A dans la CITE 2011|date=2016-01-25|url=http://dx.doi.org/10.1787/9789264248823-16-fr|work=Guide opérationnel CITE 2011|pages=117–118|publisher=OECD|doi=10.1787/9789264248823-16-fr|isbn=9789264248830|access-date=2021-09-10}}</ref><ref>{{Cite web|title=Bayelsa State, Nigeria Genealogy|url=https://www.familysearch.org/wiki/en/Bayelsa_State,_Nigeria_Genealogy|access-date=2021-09-10|website=FamilySearch Wiki|language=en}}</ref>
 
[[:en:Ijaw_people|Èdè Ijaw]],<ref>{{Cite web|title=Background Report: The Destruction of Odi and Rape in Choba|url=https://www.hrw.org/legacy/press/1999/dec/nibg1299.htm|access-date=2021-09-10|website=www.hrw.org}}</ref> ni ó gbòòrò jù ní sísọ Ìpínlẹ̀ Bayelsa pẹ̀lú [[:en:Isoko_language|Isoko]] àti [[:en:Urhobo_language|Urhobo]] tí wọ́n sọ ní àwon ìlú àbáláyé ní Ìpínlẹ̀ náà. Ó jẹ́ ìlú àbáláyé fún àwọn ará [[:en:Urhobo_people|Urhobo]] tí wọ́n wà ní agbègbè ìjọba ìbílè [[:en:Sagbama|Sagbama]].<ref>{{Cite web|title=Our Story|url=https://www.ipobinusa.org/ourstory|access-date=2021-03-07|website=Indigenous People of Biafra USA|language=en-US}}</ref> Ó jẹ́ [[Àwọn Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà|Ìpínlẹ̀]] tí ó kéré jùlọ ní orílè-èdè [[Nàìjíríà]]<ref>{{Cite web|title=Central Bank of Nigeria {{!}} Home|url=https://www.cbn.gov.ng/|access-date=2022-03-09|website=www.cbn.gov.ng}}</ref> Gẹ́gẹ́ bí àbájáde ètò-ìkànìyàn ọdún 2006, bákan náà ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè tí ó kéré jù ni ààyè.<ref name=":1" /> Wíwà rẹ̀ ní agbègbe [[:en:Niger_Delta|Niger Delta]], Ìpínlẹ̀ Bayelsa ní odò àti ọ̀gbun níbi tí òkun tí pàdé, pẹ̀lú oríṣiríṣi omi láàárin Ìpínlẹ̀ náà ní èyí tí kò jẹ́ kí ìdàgbàsókè òpópónà tó ṣe gbòógì ó wáyé.<ref>{{Cite web|date=2020-09-15|title=Bayelsa|url=https://nigeria.tourismagency.net/location/africa/nigeria/bayelsa/|access-date=2021-09-10|website=Nigeria|language=en-GB}}</ref>
 
==Àwọn Ìtọ́kasí==