Ìpínlẹ̀ Enugu: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 22 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q3817714 (translate me)
Atunkọ arokọ
Ìlà 106:
|blank_info =NG-EN
}}
'''Ìpínlẹ̀ Enugu''' (Igbo: ''Ȯra Enugu'') jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]], tí ó pín ààlà sí àríwá pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Benue àti Ìpínlẹ̀ Kogi, Ìpínlẹ̀ Ebonyi sí ìlà-oòrùn àti gúúsù-ìlà-oòrùn, pínlẹ̀ Abia sí gúúsù, àti Ìpínlẹ̀ Anambra sí ìwọ̀-oòrùn. Ìpínlẹ̀ náà gba orúkọ rẹ̀ látara olú-ìlú rẹ̀ àti ìlú tí ó gbòòrò jù, tí ń ṣe Enugu.
'''Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu''' je ikan ninu [[Awon Ipinle Naijiria|awon Ipinle 36]] ni orile-ede [[Naijiria]].
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
Laaarin [[Àwọn Ìpínlẹ̀ Nàìjíríà|àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì]] ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ìpínlẹ̀ Kogi jẹ́ ìpínlẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlọ́gbọ̀n tí ó gbòòrò jùlọ ní ààyè tàbí agbègbè àti ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún ní iye pẹ̀lú ènìyàn tí ó tó mílíọ́nnù mẹ́rin-àbọ̀dín-ni-díẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àbájáde ọdún 2016.<ref>{{Cite web|last=State|first=Enugu|date=2015-08-18|title=About Enugu state|url=https://www.enugustate.gov.ng/index.php/elements-devices/|access-date=2022-02-25|language=en-US}}</ref><ref>{{cite web|title=Population 2006-2016|url=https://nigerianstat.gov.ng/elibrary/read/474|website=[[National Bureau of Statistics, Nigeria|National Bureau of Statistics]]|access-date=22 December 2021}}</ref>
 
Láyé òde-òní Ìpínlẹ̀ Enugu ní olùgbé láti bí ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn kúnfún àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà pẹ̀lú, pàápàá àwọn ará [[:en:Igbo_people|Igbo]] pẹ̀lú díẹ̀ wọn ti wọ́n jẹ́ àwọn ará [[:en:Idoma_people|Idoma]] àti [[:en:Igala_people|Igala]] ní Etteh Uno.
 
Lẹ́yìn òmìnira ní ọdún 1960, agbègbè tí ó wá di Enugu báyìí wáà lára agbègbè ìlà-oòrùn tí wọ́n ti ní òmìnira títí di ọdún 1967 nígbàtí ekù náà pín tí agbègbè náà di apá kan ti Ìpínlẹ̀ àáríngbùngbùn ìlà-oòrùn.
 
Ninu ètò ọrọ̀-ajé, Ìpínlẹ̀ Enugu mú iṣẹ́ òwò ṣíṣe àti ọ̀gbìn lókùnkúndùn, pàápàá ọ̀pọ̀ [[:en:Yam_(vegetable)|isu]], [[:en:Rice|ìrẹsì]], [[:en:Cocoyam|kókò]], [[:en:Oil_palm|epo pupa]], àti [[:en:Cassava|ẹ̀gẹ́]]. A key minor industry was mining, especially of [[:en:Coal|coal]] in the [[:en:Udi_Hills|Udi Hills]] around the city of [[:en:Enugu|Enugu]]. Ìpínlẹ̀ Enugu ní Ìtọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn ní ìdá kẹwàá tó ga jù lọ ní orílẹ̀-èdè, wọ́n sì kà á sí ọkàn nínú [[:en:Igboland|ilẹ̀ Igbo]] tí ó jẹ́ agbègbè ẹkù àṣà ẹ̀ya [[:en:Igbo_people|Igbo]].<ref>{{cite web|title=Human Development Indices|url=https://globaldatalab.org/shdi/shdi/|website=Global Data Lab|access-date=15 December 2021}}</ref>{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
== Itokasi ==
{{reflist}}