Ìpínlẹ̀ Kaduna: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
àtunṣe àmì ọ̀rọ̀
Àtúnṣe
Ìlà 69:
}}
 
'''Ìpínlẹ̀ Kàdúná''' jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn [[Awon Ipinle Naijiria|Ìpínlẹ̀]] mẹ́rìdínlógójì ní orílẹ̀-èdè [[Naijiria|Nàìjíría]]̀. Ìpínlẹ̀ Kàdúná jẹ́ ọkan lára ìpínlẹ̀ tó wà ní apá Àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú ìpínlẹ̀ yìí ń bá a jórúkọ, ìlú Kàdúná, èyí tí ó jẹ́ ìlú kẹ́jọ tí ó tóbi jù ní orílẹ̀-èdè yìí ní ọdún 2006. Wọ́n dá ìpínlẹ̀ yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ìpínlẹ̀ àárín-gbùngbùn Àríwá ní ọdún 1967, èyí tí ó yíká Ìpínlẹ̀ Katsina òde-òní. Ní ọdún 1987 ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná ṣẹ ààlà-ọ̀nà wọn. Ìnagijẹ Kàdúná ní ''Center of learnig'' (Ilé fún ẹ̀kọ́). Orúkọ yìí ṣe rẹ́gí wọn Nítorí ọ̀pọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ tó ní kìmí ni ó wà ní ìpínlẹ̀ náà, àpẹẹrẹ ní [[Ahmadu Bello University]].<ref name=":1" />
'''Ìpínlẹ̀ Kàdúná''' jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn [[Awon Ipinle Naijiria|Ìpínlẹ̀]] mẹ́rìdínlógójì ní orílẹ̀-èdè [[Naijiria|Nàìjíría]]̀.
 
Ìpínlẹ̀ Kàdúná òde-òní jẹ́ ilé ìṣura fún àwọn ohun ìlàjú ilẹ̀ Áfíríkà, kódà, [[Nok culture|Nok civilization]] tí ó gbèrú láti c.[[1500s BC (decade)|1500 BC]] sí c. [[AD 500|500 AD]] náà wà ní bẹ̀.<ref name="PB 2014">Breunig, Peter. 2014. Nok: African Sculpture in Archaeological Context: p. 21.</ref><ref name="FB 1969">Fagg, Bernard. 1969. Recent work in west Africa: New light on the Nok culture. World Archaeology 1(1): 41–50.</ref> Ní séntúrì 9th, òwúlẹ̀-wútàn tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ [[Ya'qubi]] ṣe àkọsílẹ̀ ìwàláyé Ìjọba Hausa, èyí tí ó wà kí wón tó sọ ọ́ di [[Sokoto Caliphate]] ní ọdún 1800 lẹ́yìn ìjà àwọn Fulani.<ref>{{Cite journal|last=Nwabara|first=Samuel|date=1963|title=The Fulani conquest and rule of the Hausa Kingdom of Northern Nigeria (1804–1900)|url=https://www.persee.fr/doc/jafr_0037-9166_1963_num_33_2_1370|journal=Journal des Africanistes|volume=33|issue=2|pages=231–242|doi=10.3406/jafr.1963.1370|access-date=8 December 2021|archive-date=1 November 2020|archive-url=https://web.archive.org/web/20201101073742/https://www.persee.fr/doc/jafr_0037-9166_1963_num_33_2_1370|url-status=live}}</ref> Ní àkókò ìmúnisìn, àwọn olùdarí ilẹ̀- Britain sọ Kàdúná di olú-ìlú Àbọ̀ ní Àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. {{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
 
==Itokasi==