Ìpínlẹ̀ Imo: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Legobot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q842939 (translate me)
Atunkọ arokọ
Ìlà 68:
| footnotes = {{note|prelim|1}} Preliminary results
}}
'''Ìpínlẹ̀ Imo''' ({{lang-ig|Ȯra Imo}}) jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]], tí ó pín ààlà sí àríwá pẹ̀lú Ìpínlẹ [[:en:Anambra_State|Anambra]], Ìpínlẹ̀ [[:en:Rivers_State|Rivers]] sí ìwọ̀-oòrùn àti gúúsù, àti Ìpínlẹ̀ [[:en:Abia_State|Abia]] sí ìlà-oòrùn.<ref>{{Cite web|title=Imo {{!}} state, Nigeria {{!}} Britannica|url=https://www.britannica.com/place/Imo|access-date=2022-03-12|website=www.britannica.com|language=en}}</ref> Ó mú orukọ rẹ látara odò [[:en:Imo_River|Imo]] tí ó ń sàn jákèjádò ààlà ìlà-oòrùn. Olú-ìlú ìpínlẹ̀ náà ni [[:en:Owerri|Owerri]] tí orúkọ ìnagigẹ rẹ̀ ń jẹ́ "ọkàn ìlà-oòrùn" "Eastern Heartland."<ref>{{Cite web|title=Nigeria's 36 States and Their Slogans|url=https://nigerianfinder.com/nigerias-36-states-and-their-slogans/|access-date=2022-03-12|website=nigerianfinder.com}}</ref>
'''Ipinle Imo''' je ikan larin [[Awon Ipinle Naijiria|awon ipinle ijoba merindinlogoji]] ni orile-ede [[Naijiria]].
 
Laaarin àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ìpínlẹ̀ Imo jẹ́ ìpínlẹ̀ kẹta tí ó kéré jùlọ ní ààyè tàbí agbègbè àti ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlá ní iye pẹ̀lú ènìyàn tí ó tó mílíọ́nnù-márùn-únlé-ní-ọgọ́rùn-lọ́nàerínwó gẹ́gẹ́ bí àbájáde ọdún 2016.<ref>{{Cite web|title=Nigeria Population 2022 (Demographics, Maps, Graphs)|url=https://worldpopulationreview.com/countries/nigeria-population|access-date=2022-09-03|website=worldpopulationreview.com}}</ref>
 
Lóde-òní ìpínlẹ̀ Imo ní àwọn olùgbé láti bí ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn kúnfún àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà, pàápàá àwọn ará [[:en:Igbo_people|Igbo]] pẹ̀lú èdè [[:en:Igbo_language|Igbo]] tí ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí èdè àkọ́kọ́ ní ìfẹ̀gbẹ̀kẹg̀bẹ́ pẹ̀lú èdè Gẹ̀ẹ́sì jákèjádò ìpínlẹ̀ náà. Ṣáájú àkókò ìmúnisìn, ohun tí ó ń jẹ́ Ìpínlẹ̀ Imo ní báyìí jẹ́ apákan ti ìjọba àtijọ́ ti Nri àti Aro Confederacy nígbà míì ṣáájú kí wọ́n tó ṣẹ́gun lẹ́yìn-òrẹyìn ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdùn 1900 nípasẹ̀ àwọn ọmọ ogun ìlu Gẹ̀ẹ́sì ní Ogun Anglo-Aro. Lẹ́yìn ogun náà, àwọn ará ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì dá agbègbè náà sí Gúúsù Nàìjíríà lábẹ́ àbẹ̀ àwọn aláwọfunfu ni èyí tí ó wá dà Nàìjíríà àti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pọ̀ ní ọdún 1914; lẹ́yìn ìdàpọ̀ náà, Imo di àáríngbùngbùn fún ìdẹ́kun-ìmúnisìn nígbà Ogun àwọn Obìnrin.<ref>{{Cite web|date=2009-03-27|title=Aba Women's Riots (November-December 1929) •|url=https://www.blackpast.org/global-african-history/aba-womens-riots-november-december-1929/|access-date=2022-09-03|language=en-US}}</ref>
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}