Phasianidae: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Replacing Satyr_Tragopan_Osaka.jpg with File:Satyr_Tragopan_2.jpg (by CommonsDelinker because: Duplicate: Exact or scaled-down duplicate: c::File:Satyr Tragopan 2.jpg).
 
Ìlà 1:
[[file:Satyr Tragopan Osaka2.jpg|thumb|Satyr]]
'''Phasianidae ''' jẹ́ àwọn ẹyẹ tí ó ń gbé inú ilẹ̀ bi àwọn ẹyẹ àparò, ẹye ìgà, adìyẹ igbó, àwọn adìyẹ, ẹyẹ bí adìyẹ awó , àti ẹyẹ pòpòndò . Ọ́pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹyẹ fún ìdáraya nió wà ní ẹbí yìí.<ref name="McGowan1994">{{Cite book|isbn=84-87334-15-6|year=1994|title=New World Vultures to Guineafowl|chapter=Family Phasianidae (Pheasants and Partridges)|series=Handbook of the Birds of the World|volume=2|pages=434–479|last1=McGowan|first1=P. J. K.|editor1-last=del Hoyo|editor1-first=J.|editor2-last=Elliot|editor2-first=A.|editor3-last=Sargatal|editor3-first=J.|publisher=Lynx Edicions|city=Barcelona}}</ref> Ẹbí yìí tóbi púpọ̀, lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, wọ́n máa ń pín wọn sí àwọn mọlẹ́bí méjì, Phasianinae, àti Perdicinae. Nígbàmíràn, wọ́n máa ń tọ́jú àwọn ẹbí àti ẹyẹ míràn bí ẹbí yìí. Fún àpẹẹrẹ,<span class="cx-segment" data-segmentid="300"></span> àwọn ààjọ  American Ornithologists Union kó àwọn Tetraonidae (grouse), Numididae (ẹyẹ awó), àti Meleagrididae (àwọn tòlótòló) as bíi mọ̀lẹ́bí ní ẹbí Phasianidae.