Ìpínlẹ̀ Ògùn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 99:
 
== Àwọn ènìyàn tó ti jáde ní ìpínlẹ̀ Ògùn ==
Ìpínlẹ̀ Ògún jẹ́ dídílẹ̀ láti ọwọ́ ìjọba Murtala/Ọbásanjọ́ ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kejì, ọdún 1976 látara níhàa ìwọ̀Ìwọ̀-oòrùnOòrùn àtijọ́. Wọ́n sọ ìpínlẹ̀ náà lẹ́yìn odò Ògùn, tí odò náà sànṣàn káàkiri ìpínlẹ̀ náà láti Àríwá lọ sí Gúúsù. Ìpínlẹ̀ náà ní àyíká ìgbìmọ̀ ìjọba agbègbè ogún lọ́wọ́lọ́wọ́. Ìpínlẹ̀ Ògùn ní ọwọ́ ajẹmọ́-ìran mẹ́fà tótóbitó tóbi, àwọn náà ni: Ẹ̀gbá, Ìjẹ̀bú, Rẹ́mo, Ẹgbádọ̀, Àwọrí àti Ègùn. Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn kékeré mìíràn wà bí Ìkálẹ̀, Kẹ́tu, Ohori àti Anago.<ref>{{cite web|date=2017-07-27|title=6 Important Facts about Ogun State You Probably Didn't Know|url=https://www.vanguardngr.com/2017/07/6-important-facts-about-ogun-state-you-probably-didnt-know/|access-date=2021-12-06|website=Vanguard News|language=en-US}}</ref> Ìwé- ìpamọ́ jẹ́ẹ̀rí pé ìpínlẹ̀ yìí ló ní Fáṣítì Àdáni àti ilé-ìwé gíga ní Nàìjíríà àti ìpínlẹ̀ tó ní Fáṣítì ìpínlẹ̀ ara rẹ̀ méjì ni [[Nàìjíríà]]. Ìpínlẹ̀ Ògùn tún jẹ́ ilé fún Fáṣítì fún Ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ àti ìgbẹ̀yìn.<ref name="School Drillers 2021">{{cite web|title=List of Tribes & Local Government in Ogun State Nigeria.|website=School Drillers|date=2021-02-22|url=https://www.schooldrillers.com/tribes-local-government-in-ogun/|access-date=2022-04-20}}</ref> <ref name="Nigeriagalleria 1976">{{cite web|title=Brief History of Ogun State:: Nigeria Information & Guide|website=Nigeriagalleria|date=1976-02-03|url=https://www.nigeriagalleria.com/Nigeria/States_Nigeria/Ogun/Brief-History-of-Ogun-State.html#:~:text=Ogun%20State%20was%20created%20from,it's%20capital%20and%20largest%20city.|access-date=2022-04-20}}</ref>
 
Ìpínlẹ̀ Ògùn tí pèsè ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olórí ìjọba ní Gúúsù-Ìwọ̀nÌwọ̀ Oòrùn. Gbogbo àwọn ara Gúúsù  Ìwọ̀-Oòrùn tó ti jẹ [[Ààrẹ]] tàbí olórí ìpínlẹ̀ fún ìlú wá láti ìpínlẹ̀ Ògùn ([[Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́|Ọbásanjọ́]], Shónẹ́kàn) wọ́n gba oríyìn láti ìpínlẹ̀ Ògùn. Olóyè [[Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀|Jeremiah Ọbáfẹ́mi Àwọ́lọ́wọ̀]], Olórí àkọ́kọ́ fún Agbègbè Ìwọ̀-oòrùn, ó dẹ̀ jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ògùn. Àwọn ará Ìjẹ̀bú ní ìpínlè yìí ni àwọn Yóò á àkọ́kọ́ tó nínú ìbásepọ̀ pẹ̀lú àwọn ará úrópùEurope ní ṣẹ́ńtíúrì kẹrìnlá. Àwọn ènìyàn náà tún gbà wí pé àwọn ni ẹ̀yà Yoòbá  tó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní ma lọ owó tí a mọ̀ sí owó-Ẹyọ, tí ó jẹ́ àtawọ́gbà ní gbogbo ilẹ̀ Yorùbá kí wọ́n tí rópòrọ́pò rẹ̀ pẹ̀lú kọ́ìsì nígbà tí àwọn úrópùEurope dẹ́.<ref name="Vanguard News 2017">{{cite web|title=6 Important Facts about Ogun State You Probably Didn’t Know|website=Vanguard News|date=2017-07-27|url=https://www.vanguardngr.com/2017/07/6-important-facts-about-ogun-state-you-probably-didnt-know/|access-date=2022-04-20}}</ref>
 
==Àwọn ìtọ́kasí==