Ìpínlẹ̀ Ògùn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 97:
* [[Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Yewa]]
* [[Agbegbe Ijoba Ibile Guusu Yewa]]/Ilaro
 
== Àwọn ilé ẹ̀kọ́ ==
Ìpínlẹ̀ Ògùn ní ilé-ìwé ìjọba àpapọ̀ mẹ́ta, àwọn ni; Federal Government Girls' College, [[Sagamu]] <ref>{{cite web|title=Federal Government Girls College, Sagamu {{!}} School Website|url=https://www.fggcsagamu.org.ng/|website=www.fggcsagamu.org.ng|access-date=2020-05-24}}</ref> àti Federal Government College, [[Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Odogbolu]]<ref>{{cite web|title=Federal Government College, Odogbolu {{!}} School Website|url=https://fgcodogbolu.com.ng/|website=fgcodogbolu.com.ng|access-date=2020-05-24}}</ref> àti Federal Science and Technical College, Ijebu-Imushin.<ref>{{cite web|title=Federal Science And Technical College, Ijebu Imushin {{!}} School Website|url=https://fstcijebuimusin.com/|website=fstcijebuimusin.com|access-date=2020-05-24}}</ref>
 
Ìpínlẹ̀ náà ní Yunifásitì ìjọba àpapọ̀ kan, tí ń ṣe; [[Federal University of Agriculture, Abeokuta|Federal University of Agriculture]], [[Abẹ́òkúta|Abeokuta]] (FUNAAB<ref>{{cite web|url=https://unaab.edu.ng/|title=Federal University of Agriculture, Abeokuta, teaching, learning, research|access-date=Aug 6, 2020}}</ref>) àti college of education tó jẹ́ ti ìjọba àpapọ̀ kan, tí ń ṣe FCE Osiele (méjèèjì wà ní [[Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Odeda]]), college of education kan, tó jẹ́ ti ìjọba ìpínlẹ̀ náà, tí wọ́n fi sọrí ọ̀jọ̀gbọ́n kan tó ti ṣaláìsì báyìí, tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ [[Tai Solarin|Augustus Taiwo Solarin]] tí wọ́n dá kalè ní ọdún 1994, tí wọ́n pè ní [[Tai Solarin University of Education]]#(TASCE<ref>{{cite web|url=https://tasce.edu.ng/|title=:::TASCE|website=tasce.edu.ng|access-date=Aug 6, 2020}}</ref>. Ó tún ní Polytechnic kan ní Ilaro, tó jẹ́ ti ìjọba àpapọ̀., tí wọ́n fi sọrí oníṣòwò ilẹ̀ [[Nàìjíríà]] àti olúborí ìdíje òṣèlú ti June 12, 1993, tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Basorun [[M. K. O. Abíọ́lá|Moshood Kasimawo Olawale Abiola]], tí wọ́n pè ní [[Moshood Abiola Polytechnic]] (MAPOLY<ref>{{cite web|url=https://mapoly.edu.ng/web/|title=Moshood Abiola Polytechnic|access-date=Aug 6, 2020}}</ref>), tí ó fìgbà kan jẹ́ Ogun State Polytechnic, Ojere, [[Abeokuta]]. Àwọn mìíràn ni Another Gateway Polytechnic Saapade,<ref name="net.nbte.gov.ng">{{cite web|title=List of NBTE approved State government owned Polytechnics in Nigeria|url=https://net.nbte.gov.ng/state%20polytechnics|website=NBTE portal}}</ref> Remo (GAPOSA), Abraham Adesanya Polytechnic<ref name="net.nbte.gov.ng" /> Ijebu-Igbo (Aapoly) (tí ó fìgbà kan jẹ́ 'The Polytechnic Ijebu-Igbo) tí wọ́n fi sọrí [[Abraham Adesanya|Chief Abraham Aderibigbe Adesanya]], tó jẹ́ olóṣèlú ilẹ̀ [[Nàìjíríà]], agbẹjọ́rò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn.
 
== Àwọn ènìyàn tó ti jáde ní ìpínlẹ̀ Ògùn ==