Ìpínlẹ̀ Ògùn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 130:
=== Ilé-ìwòsàn ===
Ìpínlẹ̀ náà ní ilé-ìwòsàn tó jẹ́ ti ìjọba méjì, tí ń ṣe: [[Federal Medical Center, Abeokuta|Federal Medical Center]] ní ìlú Abeokuta, àti [[Olabisi Onabanjo University Teaching Hospital]] ní [[Sagamu]].
 
=== Àwọn ilé-ìjọsìn tó gbajúmọ̀ ===
 
* [[Sungbo's Eredo|Bilikisu Sungbo Shrine]], ní Oke-Eiri, lágbègbè Ijebu-Ode. Ibí yìí ní àwọn Ijebu gbàgbọ́ pé wọ́n sin <ref>Sungbo Eredo and Its Ecotourism Values: Sonubi O K (2009)</ref> [[Queen of Sheba]] tí wọ́n tún máa ń pè ní Bilikisu alága Wúrà. Ó jẹ́ ibi ọ̀wọ̀ àti ààyè tí àwọn oníṣẹ̀ṣe yà sọ́tọ̀. Àwọn Mùsùlùmí àti Kìrìsìtẹ́ẹ́nì ló máa ń lọ ibẹ̀.
* [[Church of the Lord (Aladura)]], [[Ogere Remo]]
* [[Redemption Camp]] (Lagos Ibadan Express Road)
* [[Living Faith Church Worldwide]], (Canaanland, Km. 10, Idiroko Road, Ota, Ogun State, Nigeria)
 
=== Gbàgede NYSC ===