Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
k interwiki
Ìlà 1:
Ogagun to feyinti, Oloye Olusegun Obasanjo, ni Aare Orile-ede Nigeria lowolowo. Eyi ni igba keji ti Baba Obasanjo yoo je Aare orile-ede Nigeria. Obasanjo ni Aare laarin odun 1976 si 1979. Oun ni Ogagun akoko ti o da ijoba pada fun awon alagbada. Leyin ti o feyinti, o bere ise adase tire, iyen ni ise agbe. Ile-ise agbe re, iyen Obasanjo Farms, gbooro; o fere ma si abala ise agbe ti ko si nibe. Laarin odun 1976 si 1999, oruko Obasanjo di eni mimo ni gbogbo agbaye. Akinkanju ni ninu eto oselu agbaye. O wa ninu awon Igbimo to n petu si aawo ni awon orile-ede to n jagun, paapaa ni ile adulawo. O je ogunna gbongbo ninu egbe kan to koriira iwa ibaje, iyen ni Transparency International. Ni odun 1999, Obasanjo tun di aare alagbada fun orile-ede Naijiria, labe asia egbe PDP. A tun fi ibo yan an pada gege bi aare ni 2003. Okan pataki ninu afojusun ijoba Obasanjo ni igbogun ti iwa jegudujera (Anti-Corruption). Obasanjo gbiyanju dida ogo Naijiria pada laarin awon akegbe re ni agbaye (Committee of nations). O tun iyi owo naira to ti di aburunmu bi gaari omí se, gbigbowo-lori-oja (inflation) ti dinku jojo. Iye owo afipamo-soke-okun (external reserves) Naijiria ti ga gan-an ni, o to $40 billion bayii. Obasanjo tun fidi awon banki wa mule, pipo ti won po yeeriye tele ti dinku, won o ju meeedogbon lo mo bayii. Eyi mu ki awon eniyan ni igbekele ni fifi owo pamo si banki, won si tun le ya owo fun idagbasoke okowo won gbogbo. Lara awon eto ti ijoba Obasanjo n se ni tita awon ogun ijoba fun awon aladaani (''privatisation policy''). Eto yii ku die kaato. Idi ni pe awon olowo lo le ra awon ogun bee, talika kankan ko le ra won.
 
[[en:Olusegun Obasanjo]]