Ìbínibí: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created page with ''''Ilẹ̀abínibí''' je agbajo awon eniyan ti won ni ibapinpo gidi tabi tikosi itan kanna, asa, ede tabi orisun.<ref>"Nation", ''The New Oxford American Dictionary'', Secon...'
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 06:34, 20 Oṣù Kejìlá 2009

Ilẹ̀abínibí je agbajo awon eniyan ti won ni ibapinpo gidi tabi tikosi itan kanna, asa, ede tabi orisun.[1] Idagbasoke ati isegbejadeimo ileabinibi je bibatan gbagbagba mo idagbasoke awon idimusejoba tonile-ese elero ayeodeoni ati awon egbe imurinkankan onileabinibi ni Europe ni awon odunrun 18jo ati 19sa,[2] botilejepe awon asonileabinibi n fa ileabinibi lo si ijohun lori ila itan jijapo.[3]




Itokasi

  1. "Nation", The New Oxford American Dictionary, Second Edn., Erin McKean (editor), 2051 pages, May 2005, Oxford University Press, ISBN 0-19-517077-6.
  2. Dictionary of the History of Ideas: s.v. "Nationalism"
  3. Fun apere imukede aigbarale ti awon ara Irelandi Thus the Irish Declaration of Independence fa akitiyan awon ara Irelandi si ijobalelori awon ara Geesi de bi odun 700.