Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Àyèọmọìlú"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
(Created page with ''''Àyèọmọìlú''' ni ipo jije omoilu alawujo, oloselu tabi awujo onibinibi pato kan. Ijewiwa ni ayeomoilu ninu iro adehun alawujo gbe pelu re, awon eto ati ojuse. [[A...')
 
'''Àyèọmọìlú''' ni ipo jije omoilu alawujo, oloselu tabi awujo onibinibi pato kan.
 
Ijewiwa ni ayeomoilu ninu [[iro adehun alawujo]] gbe pelu re, awon eto ati ojuse. [[Aṣe àyèọmọìlú]] ni imoye pe awon omiluomoilu gbodo sise fun idaraju awujo won nipa kikopa ninu okowo, ise igboro, ise aladase, ati iru igbera baun lati mudara igbesiaye fun gbogbo omoilu.