Ìṣèlú: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 3:
 
==ÌSÈLÚ NILE YORUBA==
Ní àwùjo Yorùbá, á ní àwon ònà ìsèlú tiwa tí ó dá wa yàtò sí èyà tàbí ìran mìíràn. Kí àwon Òyìnbó tó dé ní àwa Yorùbá ti ni ètò ìsèlú tiwa tí ó fesèmúlè. Tí ó sì wà láàárin òpò àwon ènìyàn. Yàtò sí tí àwon èyà bí i ti ìgbò tí ó jé wí pé àjorò ni won n fi ìjoba tiwon se (acephalous) tàbí ti Hausa níbi tí àse pípa wà lówó enìkan (centralization).
 
Ètò òsèlú Yorùbá bèrè láti inú ilé. Eyi si fi ipá tí àwon òbí ń kò nínú ilé se ìpìlè ètò òsèlú wa. Yorùbá bò won ní, “ilé là á tí kó èsó ròdé”.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ìṣèlú"