Èdè Bàlóṣì: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: Bàlúsì tàbí Bàlósì Baluchi or Balochi Omo egbé èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúsì. Àwon tí ó ń so ó tó mílíònù m...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 15:37, 12 Oṣù Kínní 2007

Bàlúsì tàbí Bàlósì

Baluchi or Balochi

Omo egbé èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúsì. Àwon tí ó ń so ó tó mílíònù márùn-ún. Púpò nínú àwon tí ó ń so ó yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúsísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlè (province) tí ó wà ní apá ìwò-oòrùn jùní pakcstan. Àwon tí ó ń so èdè yìí ní Baluchistan tó múlíònù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkotó Lárúbáwá (Arabic) ni wón fi ko ó sílè. Àjo kan wà tí wón ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkosílè èdè yìí páye.