Genevieve Nnaji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

k (Bot Fífikún: af:Genevieve Nnaji)
Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tódárajùlọ fún 2001 ní City People Awards, ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà.
 
Ní 2004, ó tọwọ́bọ̀wé pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ àwo-orin ilẹ̀ [[Ghana]], ''EKB Records'' láti gbé àwo-orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde tó ún jẹ́ ''One Logologo Line'',<ref>[http://www.stayaround.com/genevieve-artist-660.html Genevieve at Blue Pie Productions]</ref> àdàlú orin ''R&B'', ''[[Hip-Hop]]'' àti ''Urban''.<ref>[http://www.mtraks.com/artist/genevieve/release/43321-one_logologo_line Genevieve: One Logologo Line]</ref>
 
Ní 2008 ni ó ṣí ilé ìránsọ rẹ̀ tó ún jẹ́ "St. Genevieve", èyí tó ún ṣọrẹ ìdámẹ́ẹ̀wá èrè rẹ̀.<ref>[http://naijashowbiz.com/archives.html Genevieve starts clothing line]</ref><ref>[http://www.talkzimbabwe.com/news/122/ARTICLE/2692/2008-06-15.html Genevieve Nnaji at TalkZimbabwe.com]</ref><ref>[http://niyitabiti.blogspot.com/2008/05/nollywood-star-actressgenevieve-nnaji.html Genevieve Nnaji at Gistmaster.com]</ref>