Kongo: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: KONGO Èdè tí àwon ènìyàn wònyí ń so ni Kitumba, òun ta ń pè ní Kongó ní n nkan se pèlú àpapò àwon èdè Bantu. Àwon ibi tí ati n so...
 
No edit summary
Ìlà 1:
[[KONGO]]
 
==A==
 
Èdè tí àwon ènìyàn wònyí ń so ni Kitumba, òun ta ń pè ní Kongó ní n nkan se pèlú àpapò àwon èdè Bantu. Àwon ibi tí ati n so èdè yìí ni: Angola, Congo, Crabon ati Zoure.
Ní àarin odún (1960) sí Odún (1996) àwon tí ó n so èdè yìí dín díè ni mílíònù mókànlá. Àkotó èdè won muná dóko; sùgbón won kìí lo àmì ohùn lórí gbogbo òrò won. Àkoto won tó wuyì yìí lo mú kí ohun èdè won dín kù ní lílò.
 
==B==
 
Èdè Kongo
 
Kongo tàbí Kikongo – ó jé èdè Bantu, àwon ènìyàn Bakongo ni won ń so ó. Ààrin ilè Afíríkà ni ó wà. Àwon tí wón ń so ó jé mílíònù méje òpòlopò àwon tí wón kó ní erú ní ilè Afíríkà tí wón sì tà wón fún America ni wón ń so èdè yìí. Àwon bí i mílíònù ni wón ń lo èdè yìí gégé bí èdè méjì.
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Kongo"