Peter Obi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
No edit summary
No edit summary
|Educational background =
}}
'''Peter Obi''' (19 July, 1961) je oloselu omo ile [[Naijiria]], ohun si ni lati 2006 Gomina [[Ipinle Anambra]]. O je omo egbe oloselu [[APGA]]. Won diboyan Obi fun igba keji gege bi [[List of governors of Anambra State|Gomina Ipinle Anambra]] ni idiboyan to waye ni 6 February, 2010<ref>[http://234next.com/csp/cms/sites/Next/News/National/5523860-146/story.csp Obi defeats PDP machine]</ref>, Obi pelu ibo 97,843 bori [[Chris Ngige]] (AC) to gba ibo 60,240, ati [[Charles Soludo]] (PDP), nipo keta to gba ibo 59,365.