Senegal: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 67:
|footnotes =
}}
'''Sẹ̀nẹ̀gàl''' ({{lang-fr|le Sénégal}}) tabi '''Orile-ede Olominira ile Senegal''' je orile-ede ni [[Iwoorun Afrika]]. Senegal ni [[Atlantic Ocean|Okun Atlantiki]] ni iwoorun, [[Mauritania]] ni ariwa, [[Mali]] ni ilaorun, ati [[Guinea]] ati [[GineaGuinea-Bissau]] ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo [[Gambia]] ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia<ref>[[Gambia]] lies almost entirely within Senegal, surrounded by it on the north, east and south; from its western coast, Gambia's territory follows the [[Gambia River]] more than 300&nbsp;kilometres (186&nbsp;miles) inland.</ref> Ifesi ile Senegal fe to 197,000&nbsp;km², be si ni o ni onibugbe bi 13.7 legbegberun.
 
[[Dakar]] ni oluilu re to wa lori [[Cap-Vert|Cap-Vert Peninsula]] ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.<ref>[http://hdr.undp.org/en/media/HDI_2008_EN_Tables.pdf ''Human Development Indices''], Table 3: Human and income poverty, p. 35. Retrieved on 1 June 2009</ref>
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Senegal"