Ìwọ́ ìtanná: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 13:
== Ìwọ́ iná nínú okùn onírin (metal wire) ==
 
Nínú àwọn okùn onírin ([[Agbéiná]] - electrical conductor) tí wón gba [[agbára iná]] láàyè, ogunlọ́gọ̀ àwon [[atanná]] (electron) ni wọ́n rìn kiri lọ́fẹ̀ẹ́lófòò ([[atanná ọ̀fẹ́]]). Àwọn atanná wọ̀nyí kò sopọ̀ mọ́ [[átọ́mù]] kankan.
 
== Òfin Ohm ==
 
[[òfin Ohm|Òfin Ohm]] n tọ́kasí ìbásepọ̀ tó wà láàrin [[ìgbanná]] (Voltage), ìwọ́ iná ati [[ìdinà iná]] (electrical resistance):
 
:<math>
I = \frac {V}{R}
</math>
 
nígbàtí,
 
:''I'' jẹ́ ìwọ́ iná, ni ìwọ̀n [[ampere]]
:''V'' jẹ́ ìgbanná ([[ìyàtọ̀ ìlókun]]) (potential difference), ní ìwọ̀n [[volt]]
:''R'' jẹ́ ìdinà iná, ní ìwọ̀n [[ohm (ẹyọ)|ohm]]
 
== Àpẹrẹ ==
 
Àpẹrẹ ìwọ́ iná ti a le fojuri ni [[mọ̀nàmọ́ná]] (lightning) ati [[ìjì ojúòòrùn]] (solar wind). Bakana iwo ina ti a mọ̀ ni sisan [[atanna]] ninu okùn onírin, fun apere awon waya opo ina to n gbe ina lati ibikan de ibo miran ati awon waya kekeke ninu awon ero onina (electronics), ati bi atanna se n san koja ninu [[adena ina]] (resistor), sisan kiri [[ioni]] (ion) ninu [[bátìrì]] (battery) ati sisan kiri [[iho atanna|iho]] ninu [[agbeinadie]] (semiconductor).
 
[[Image:Electromagnetism.svg|175px|thumb|Gẹ́gẹ̀ bi [[ofin Ampère]] se sọ, ìwọ́ iná n pèsè [[pápá inágbérigbérin]].]]
== Inagberingberin (electromagnetism) ==
 
Ìwọ́ iná n pese [[pápá inágbéringbérin]] (electromagnetic field). A le wo papa gberigberin bii ọ̀pọ̀ ìlà to yi waya po.
 
 
[[ar:تيار كهربائي]]