Áljẹ́brà onígbọrọ: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
New page: '''Aljebra alatele''' je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon atokaona (vector), aaye atokaona (vector space), maapu alatele (linear map) ati awon ona idogba alatele...
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 09:41, 7 Oṣù Kẹrin 2007

Aljebra alatele je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon atokaona (vector), aaye atokaona (vector space), maapu alatele (linear map) ati awon ona idogba alatele (system of linear equation). Aaye atokaona se pataki ninu imo isiro ayeodeoni, nipa bayi aljebra alatele wulo lopolopo ninu aljebra afoyemo ati agbeyewo alabase (functional analysis). O tun wulo gidigidi ninu awon sayensi aladabaye ati sayensi awujo nigba t'oje pe awon apere alainitele (nonlinear) se mu sunmo eyi to je alatele (linear).