Áljẹ́brà onígbọrọ: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
'''Aljebra alatele''' je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon [[atokaona]] (vector), [[aaye atokaona]] (vector space), [[maapu alatele]] (linear map) ati awon [[ona idogba alatele]] (system of linear equation). Aaye atokaona se pataki ninu imo isiro ayeodeoni, nipa bayi [[aljebra]] alatele wulo lopolopo ninu [[aljebra afoyemo]] ati [[agbeyewo alabase]] (functional analysis). O tun wulo gidigidi ninu awon [[sayensi aladabaye]] ati [[sayensi awujo]] nigba t'oje pe awon apere alainitele (nonlinear) se mu sunmo eyi to je alatele (linear).
 
== Ìtàn Áljẹ́brà alátẹ̀lé ==
 
Itan aljebra ayeodeoni bere ni arin odun 1843 ati 1844. Ni odun 1843, [[William Rowan Hamilton]] (eni ti o koko soro nipa ''atokaona'') se awari ''quaternions''. Ni odun 1844, [[Hermann Grassmann]] ko iwe ni ede [[Germani]] pelu akole ''Die lineale Ausdehnungslehre''. [[Arthur Cayley]] mu [[apotinomba]] (matrix) wa ni odun 1857. [[Ilana Cramer]] to n fihan wa bi a se le s'ojutu awon [[idogba iseyato abo]] (partial differential equation) lo so aljebra alatele di eko ti a n ko ni awon ile-eko giga. Fun apere, E.T. Copson ko pe:
 
:''Ni odun 1922 ti mo di oluko kekere ni ile-eko giga Edinburgh, o yamilenu lati ri pe ilanaeto eko yato si ti ile-eko giga Oxford. Eka bi [[isodiodidi Lebesgue]] (Lebesgue integration), [[ero apotinomba]] (matrix theory), [[agbeyewo aminomba]] (numerical analysis), [[alawonile Riemannian]] (Riemannian geometry), lori awon eyi ti n ko mo nkankan nipa won....'' E.T. Copson, Oro Isaju si ''Idogba Iseyato Abo'', 1973