Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Pólàndì"

10 bytes added ,  16:42, 27 Oṣù Kẹrin 2010
k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Bot Fífikún: mi:Pōrana)
k
}}
 
'''Pólàndì''' {{Audio-IPA|en-us-Poland.ogg|/ˈpoʊlənd/}} ({{lang-pl|Polska}}), fun ibise gege bi orile-ede '''Olominira ile Poland''' (''[[Rzeczpospolita]] Polska''), je orile-ede ni [[Central Europe|Aarin Europe]] <ref>http://unstats.un.org/unsd/geoinfo/gegn23wp48.pdf</ref><ref name="cia.gov">https://www.cia.gov/library/publications/the-world-factbook/geos/pl.html</ref> to ni bode mo [[GermanyJẹ́mánì]] si iwoorun; [[Czech Republic|Tsek Olominira]] ati [[Slovakia|Slofakia]] si guusu; [[Ukraine]], [[Belarus]] ati [[Lithuania]] si ilaorun; ati [[Baltic Sea|Okun Baltiki]] pelu [[Kaliningrad Oblast]], to wa ni Rosia, ni ariwa. Gbogbo ifesi agbegbe ile Poland je {{convert|312679|km2|sqmi}},<ref name="CSO_2008">{{cite web |title=Concise Statistical Yearbook of Poland, 2008|publisher=[[Central Statistical Office (Poland)]] |date=28 July 2008 |url=http://www.stat.gov.pl/cps/rde/xbcr/gus/PUBL_maly_rocznik_statystyczny_2008.pdf |format=PDF|accessdate=2008-08-12}}</ref> to so di [[List of countries and outlying territories by total area|orile-ede 69th titobijulo]] ni aye ati ikesan titobijulo ni Europe. Poland ni iye awon eniyan to ju 38&nbsp;legbegberun lo,<ref name="CSO_2008"/> eyi so di [[List of countries by population|orile-ede 34th toleniyanjulo]] ni aye<ref>NationMaster.com 2003–2007, [http://www.nationmaster.com/country/pl-poland Poland, Facts and figures]</ref> ati ikan ninu awon toleniyanjulo ni [[European Union|Isokan Europe]].
 
Idasile orile-ede Poland bere pelu [[Christianity|Esin Kristi]] latowo [[Mieszko I of Poland|Mieszko I]] olori ibe, ni odun 966, nigbati orile-ede yi gba gbogbo aye ti Poland gba loni. [[Kingdom of Poland (1025–1385)|Ile-Oba Poland]] je didasile ni 1025, ni odun 1569 o bere long [[Polish–Lithuanian union|ajosepo]] pipe pelu [[Grand Duchy of Lithuania]] nipa titowobo [[Union of Lublin|Isokan ilu Lublin]], to sedasile [[Polish–Lithuanian Commonwealth|Ajoni Polandi ati Lithuania]].
 
Ajoni yi wo ni 1795, be sini [[Partitions of Poland|Poland je pipin]] larin [[Kingdom of Prussia|Ile-Oba Prussia]], [[Russian Empire|Ile-Oluoba Rosia]], ati [[Habsburg Monarchy|Austria]]. Poland pada gba ilominira ni [[Second Polish Republic|Igba Oselu Keji Poland]] ni 1918, leyin [[World War I|Ogun Agbaye Akoko]], sugbon o je didurolori latowo [[NaziJẹ́mánì GermanyNazi]] ati [[Soviet Union|Isokan Sofieti]] nigba [[World War II|Ogun Agbaye Keji]]. Poland pofo emin awon eniyan toju egbegberun 6 lo ninu Ogun Agbaye Keji, o bere lekansi gege bi orile-ede [[People's Republic of Poland|Olominira awon Ara ile Poland]] larin [[Eastern Bloc|Blok Ilaorun]] labe olori [[Soviet Union|Sofieti]].
 
Nigba awon [[Revolutions of 1989|Ijidide odun 1989]], ijoba [[communism|komunisti]] wolule leyin re Poland di "Oselu Keta Poland" pelu ofin ibagbepo. Poland je [[unitary state|orile-ede onisokan]], to je idipo awon [[Voivodeships of Poland|ipinle]] merindilogun ({{lang-pl|województwo}}). Poland je ikan ninu [[European Union|Isokan Europe]], [[NATO]], [[United Nations|Agbajo awo Orile-ede]], [[World Trade Organization|Agbajo Idunadura Agbaye]], ati [[Organisation for Economic Co-operation and Development|Agbajo fun Ifowosowopo Okowo ati Idagbasoke]] (OECD).