Àttílà (406 - 453) lo je oba awon Húnnì eya alarinka lati Mongolia lati odun 434 titi de 453 nigba to ku. Igba ijoba Attila ni eya Hunni di olokiki.

Attila.
Attila
Emperor of the Huns
Orí-ìtẹ́434–453
Ọjọ́ìbí406
IbíbíbísíPlace unknown
Aláìsí453 (aged 47)
Ibi tó kú síunknown, possibly in modern Hungary
AṣájúBleda and Rugila
Arọ́pọ̀Ellac
BàbáMundzuk



Itokasi àtúnṣe