Ìtanná (Electricity) ni sayensi, imo-ero, onise-ona ati àwon isele eleda to je mo bi awon adijo ina se wa ati bi won se n sanlo. Itanna n fa orisirisi isele oni-tanna, bi monamona, ina ojukan, ifasara gberingberin onina ati isanlo iwo onitanna ninu waya ina. Bakan naa, itanna gba idasile ati igbasodo iranka gberingberin onina bi awon iru radio laye.

Multiple lightning strikes on a city at night
Monamona je ikan ninu ipa itanna afojuri.

Ninu itanna, awon adijo n se awon papa onigberingberin onina ti won n sise lori awon adijo miiran. Itanna n sele nitori orisirisi awon iru siseeda:

Ninu iseero onitanna, itanna unje lilo fun:

Awon isele onitanna ti je gbigbeka lati igba aye atijo, sibesibe ilosiwaju ninu sayensi re ko sele titi di orundun ketadinlogun ati kejidinlogun. Awon imulo alamuse fun itanna sibesibe si kere, yio si di opin orundun okandinlogun ki awon oniseero o to le lo ni ile-ise ati ibugbe. Igbale iyara ninu oroiseona onitanna ni asiko yi se awon ile-ise ati awujo di otun. Nitoripe itanna se lo lorisirisi ona lati pese okun gba laye mulo ninu opo imulo alainiye bi irinna, igbegbonna, itanmole, ibanisoro, ati isirokomputa. Agbara onitanna ni igbaeyin ile-ise awujo odeoni, be si ni yio ri lojowaju.[1]


Akiyesi àtúnṣe

  1. Jones, D.A. (1991), "Electrical engineering: the backbone of society", Proceedings of the IEE: Science, Measurement and Technology, 138 (1): 1–10, doi:10.1049/ip-a-3.1991.0001 

Itokasi àtúnṣe

Ajapo ode àtúnṣe

Àdàkọ:Wiktionary