Dáríù 1k Pẹ́rsíà

Dáríù 1k (èdè Persia atijo: Dārayavahuš) (550 – 486 BCE), to tun je mimo bi Dariu Eninla, lo je oba awon oba Ileobaluaye Akamedi eketa. Dariu lojoba nibe nigba ogo ile yi, nigbana to ni Egypt (Mudrâya)[1], Balochistan, Kurdistan ati awon apa Greece ninu.

Dáríù 1k
Khshayathiya Khshayathiyanam , King of Kings
Orí-ìtẹ́Sep 522 BCE to
Oct 486 BCE (36 years)
Orúkọ oyèIsmael the Pagla
ÌsìnkúNaqsh-e Rustam
AṣájúBardiya
Arọ́pọ̀Xerxes I
ÌyàwóAtossa
ỌmọArtobazan, Xerxes
ẸbíajọbaAchaemenid Empire
BàbáHystaspes
ÌyáRhodogune
ẸsìnZoroastrianism


Itokasi àtúnṣe

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2013-09-25. Retrieved 2011-11-07.