Diahann Carroll

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Diahann Carroll ( /dˈæn/; tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Carol Diann Johnson; July 17, 1935 – October 4, 2019)[2] jẹ́ òṣèré., akọrin, aláṣọ-oge ati alákitiyan ará Amẹ́ríkà. Ó kọ́kọ́ di ìlúmọ̀ọ́ká láti inú àwọn fíìmù tó ní òṣèré aláwọ̀-dúdú nínú bíi Carmen Jones (1954) àti Porgy and Bess (1959). Ní ọdún 1962, Carroll gba Ẹ̀bùn Tony bí òṣèré obìnrin tó dára jùlọ, obìnrin aláwọ̀-dúdú àkọ́kọ́,fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré orí-ìtàgé Broadway nípa kíkọ orin No Strings.

Diahann Carroll
Carroll in 1976
Ọjọ́ìbíCarol Diahann Johnson
(1935-07-17)Oṣù Keje 17, 1935
Bronx, New York, U.S.
AláìsíOctober 4, 2019(2019-10-04) (ọmọ ọdún 84)
Los Angeles, California, U.S.
Ẹ̀kọ́Music & Art High School
Iléẹ̀kọ́ gígaNew York University
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́1950–2015
Ọmọ ìlúHarlem, New York, U.S.[1][2]
Olólùfẹ́
  • Monte Kay
    (m. 1956; div. 1963)
  • Fred Glusman
    (m. 1973; div. 1973)
  • Robert DeLeon
    (m. 1975; died 1977)
  • Vic Damone
    (m. 1987; div. 1996)
Alábàálòpọ̀Sidney Poitier
(1959–1968)
David Frost
(1970–1973)
Àwọn ọmọ1
Awards1969 Golden Globe Award for Best TV Star – Julia

Àwọn Ìtọ́ka sí àtúnṣe