Giordano Bruno (1548 – February 17, 1600), oruko abiso Filippo Bruno, je ara Italia elesin Dominiki, amoye, onimomathimatiki ati atorawo, to gbajumo bi elegbe ijeailopin agbalaaye. Awon irojinle oro-ida aye re koja afijuwe ti Koperniku lo nipa pe o pe Òrùn bi ikan ninu awon ohun agbarajo ojuorun alainiye ti won unda lo kiri: ohunni ara Europe akoko to setumo agbalaaye bi ohun ajapo nibi ti awon irawo ti a unri lale ri bakanna bi Orun. O je siseku pa pelu ijona lowo awon alase i 1600 leyin ti Ile Iwadi Romu dalebi esun ailesin to je aibofinmu nigbamo. Leyi iku re o gbajumo gidi; ni orundun 19k ati ibere orundun 20k, awon olutuwo ti won gbe awon igbagbo alatorawo re wo gba bi akoni fun ironu ominira ati awon erookan sayensi odeoni.

Giordano Bruno
OrúkọGiordano Bruno
Ìbí1548 (date not known)
Nola, Kingdom of Naples, in present-day Italy
AláìsíFebruary 17, 1600 (ọmọ ọdún 51–52)
Rome, Papal States, in present-day Italy
ÌgbàRenaissance philosophy
AgbègbèEurope
Ìjẹlógún ganganPhilosophy, Cosmology, and Memory


Itokasi àtúnṣe