Halle Berry

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Halle Berry (pípè /ˈhæli ˈbɛri/; ojoibi August 14, 1966[1]) je osere, ologe tele ati alewa ara Amerika. Berry gba Emmy, Obiriki Oniwura, SAG, ati NAACP Image Award fun Introducing Dorothy Dandridge[2] be sini o tun gba Ebun Akademi fun Obinrin Osere Todarajulo be ni o si jedidaloruko fun Ebun BAFTA ni 2001 fun isere re ninu Monster's Ball, lati di obinrin akoko omo Afrika Amerika to gba ebun fun Osere Obinrin Todarajulo.

Halle Berry
Head and shoulders shot of a smiling Berry with dark hair pulled back, wearing a lace shirt and turquoise necklace.
Berry visiting with sailors and Marines during the opening day of Fleet Week New York 2006
ÌbíOṣù Kẹjọ 14, 1966 (1966-08-14) (ọmọ ọdún 57)
Cleveland, Ohio, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ọkọ
David Justice (m. 1992–1997)

Eric Benét (m. 2001–2005)


Itokasi àtúnṣe

  1. Although a 1968 birthdate is found in Britannica and other places, she stated in interviews prior to August 2006 that she would turn 40 then. See: FemaleFirst, DarkHorizons, FilmMonthly, and see also CBS. Accessed 2007-05-05.
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named peo1