Harriet Tubman (abiso Araminta Ross; c. 1820 or 1821 – March 10, 1913) je omo Afrika Amerika to je olutudekun, aseteyan, ati oluwona nigba Ogun Abele Amerika. Leyin igba to sa kuro ni oko eru, nibi ti won bi si, o se iranlose metala lati se itusile awon eru bi 70[1] nipa lilo awon eto ati ile abo awon alakitiyan alodioko eru ti a mo si Underground Railroad. Lojo waju o ran John Brown lowo lati wa awon eniyan ti won rolu Harpers Ferry ni, o si tun sakitiyan fun eto ibo awon obinrin.

Harriet Tubman
Harriet Tubman c. 1880
Ọjọ́ìbí1820
Dorchester County, Maryland
Aláìsí(1913-03-10)Oṣù Kẹta 10, 1913
Auburn, New York
Olólùfẹ́John Tubman, Nelson Davies
Parent(s)Ben and Harriet Greene Ross


Itokasi àtúnṣe

  1. Larson, p. xvii.