José Alberto Mujica Cordano (Pípè: [xoˈse alˈβerto muˈxika korˈðano], known as El Pepe, (ojoibi May 20, 1935) je oloselu ara Uruguay to je Aare orile-ede Uruguay lowolowo.

José Mujica
President of Uruguay
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
March 1, 2010
Vice PresidentDanilo Astori
AsíwájúTabaré Vázquez
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù Kàrún 20, 1935 (1935-05-20) (ọmọ ọdún 88)
Montevideo, Uruguay
Ẹgbẹ́ olóṣèlúBroad Front
(Àwọn) olólùfẹ́Lucía Topolansky
ProfessionFarmer
Signature


Itokasi àtúnṣe