Ìpògùn tí ṣe ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá, jẹ́ ẹ̀kọ́ìwádìí ìkósínú, ìní àti ìwùwà ohun èlò.[1][2] Kẹ́místrì únsọ nípa àwọn átọ́mù àti ìbáraṣepọ̀ wọn pẹ̀lú àwọn átómù míràn, àgàgà pẹ̀lú àwọn ìní àwọn ìsopọ̀ kẹ́míkà. Kẹ́místrì tún úndálórí àwọn ìbáraṣepọ̀ láàrin àwọn átọ́mù (tàbí ọ̀pọ̀ àwọn átọ́mù) àti orísirísi irú okun (f.a. àwọn ìdaramọ́ra f fọ́tòkẹ́míkà, àwọn ìyípadà nínú ojúwà èlò, ìyàsọ́tọ̀ àwọn àdàlú, àwọn ìní pólímẹ̀r, at.b.b,lọ).

Chemicals in flasks (including Ammonium hydroxide and Nitric acid) lit in different colors

Kẹ́místrì únjẹ́ pípè nígbà míràn bíi "sáyẹ́nsì agbàrin" nítorípé ó so ìṣeẹ̀dá mọ́ àwọn sáyẹ́nsì onítaládánidá míràn bíi Jẹ́ọ́lọ́jì àti baolọ́jì.[3][4] Kẹ́místrì jẹ́ ẹ̀ka sáyẹ́nsì oníṣeẹ̀dá sùgbọ́n ó yàtọ̀ sí físíksì.[5]

Ìtumọ̀-ọ̀rọ̀ àtúnṣe

Ìtàn àtúnṣe

Àwọn òpó ìpògùn òdeòní àtúnṣe

Èlò àtúnṣe

Átọ́mù àtúnṣe

Àkọ́bẹ̀rẹ̀ àtúnṣe

Àdàpọ̀ àtúnṣe

Ounkókó àtúnṣe

Hóró àtúnṣe

Mólù àti iye àwọn ounkókó àtúnṣe

Àwon ìní àtúnṣe

Àwọn íónì àti iyọ̀ àtúnṣe

Ìjẹ́kíkan àti ìjẹ́ipìlẹ̀ àtúnṣe

Ojúìwà àtúnṣe

Ìsopọ̀ àtúnṣe

Ìtúnṣe àtúnṣe

Rẹ́dọ́ksì àtúnṣe

Àyèdídọ́gba àtúnṣe

Okun àtúnṣe

Àwọn òfin àpòpọ̀ògùn àtúnṣe

Àwọn ìtúnṣe àpòpọ̀ògùn ní àwọn òfin dájú tó ṣàkóso wọn, tí wọ́n ti dí òye àpilẹ̀sẹ̀ nínú ìpògùn. Díẹ̀ nínú wọn nìyí:

Ẹ tún wo àtúnṣe


Itokasi àtúnṣe

  1. "What is Chemistry?". Chemweb.ucc.ie. Archived from the original on 2018-10-03. Retrieved 2011-06-12. 
  2. Chemistry. (n.d.). Merriam-Webster's Medical Dictionary. Retrieved August 19, 2007.
  3. Theodore L. Brown, H. Eugene Lemay, Bruce Edward Bursten, H. Lemay. Chemistry: The Central Science. Prentice Hall; 8 edition (1999). ISBN 0-13-010310-1. Pages 3-4.
  4. Chemistry is seen as occupying an intermediate position in a hierarchy of the sciences by "reductive level" between physics and biology. See Carsten Reinhardt. Chemical Sciences in the 20th Century: Bridging Boundaries. Wiley-VCH, 2001. ISBN 3-527-30271-9. Pages 1-2.
  5. Is chemistry a branch of physics? a paper by Mario Bunge[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]

Àdàkọ:Ìbọ̀sẹ̀ sáyẹ́nṣì onítaládánidá