Karl Theodor Jaspers (February 23, 1883 – February 26, 1969) je asewosan-emin ati amoye ara Jemani to ko ipa gidi lori oro-olorun odeoni. Leyin to ko eko nipa bi a ti n se iwosan-emin, Jaspers boju de iwadi imoye, o si tiraka lati wa sistemu imoye tuntun. O je gbigba bi akede iseoniwalaaye ni Jemani, botilejepe ko faramo pipe be.

Karl Theodor Jaspers
Karl Jaspers
OrúkọKarl Theodor Jaspers
Ìbí(1883-02-23)Oṣù Kejì 23, 1883
Oldenburg, Grand Duchy of Oldenburg, Germany
AláìsíFebruary 26, 1969(1969-02-26) (ọmọ ọdún 86)
Basel, Switzerland
Ìgbà20th-century philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Existentialism, Neo-Kantianism
Ìjẹlógún ganganPsychiatry, Theology, Philosophy of History
Àròwá pàtàkìAxial Age, coined the term Existenzphilosophie, Dasein and Existenz



Itokasi àtúnṣe