Martin Heidegger (26 September 1889 – 26 May 1976) (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈmaɐ̯tiːn ˈhaɪ̯dɛɡɐ]) je onimoye to ni ipa pataki ara ile Jemani. Iwe re to ko to se koko ni, Being and Time. Heidegger si n fa ariyanjiyan nitori ipa to ko ninu Nazism ati itileyin to ni fun Adolf Hitler.

Martin Heidegger
OrúkọMartin Heidegger
Ìbí26 September 1889
Meßkirch, Germany
Aláìsí26 Oṣù Kàrún 1976 (ọmọ ọdún 86)
Freiburg im Breisgau, Germany
Ìgbà20th-century philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Phenomenology · Hermeneutics · Existentialism
Ìjẹlógún ganganOntology · Metaphysics · Art · Greek philosophy · Technology · Language · Poetry  · Thinking
Àròwá pàtàkìDasein · Gestell · Heideggerian terminology




Itokasi àtúnṣe