Pílánẹ́tì gẹ́gẹ́ bí i Ẹgbẹ́ìrẹ́pọ̀ ìmọ̀ Òfurufú Káàkiriayé (IAU) ṣe ṣè'tumọ̀ rẹ̀ jẹ́ ohun òkè-ọrùn tí ó ń yí ìrànwọ́ ká tàbí aloku ọ̀run tí tíwúwosí rẹ̀ jẹ́ kí ó rí róbótó, tí kò tóbi púpọ̀ láti yíyọ́ ìgbónáinúikùn (anthothermonuclear fusion) láàyè nínú rẹ̀, tí ó sì ti gba àwọn oríṣiríṣi ìdènà kúra cartele dé santata lọ́nà tí ó ń gbà kọjá.

Awon Planeti mejeejo

Àwọn Pílánẹ́tì tí ó wà nínú Ètò Òòrùn àtúnṣe

Gẹ́gẹ́ bí (IAU) ṣe sọ, pílánẹ́tì mẹ́jọ ni wọ́n wà nínú ètò òòrùn. Àwọn nìwọ̀nyìí bí wọ́n ṣe ń jìnnà sí Òòrùn:

Èdè Yorùbá àtúnṣe

  1. ( ) Mẹ́rkúríù
  2. ( ) Àgùàlà
  3. ( ) Ilẹ̀-ayé
  4. ( ) Mársì
  5. ( ) Júpítérì
  6. ( ) Sátúrnù
  7. ( ) Úránù
  8. ( ) Nẹ́ptúnù

Èdè Gẹ̀ẹ́sì àtúnṣe

  1.   Mercury
  2.   Venus
  3.   Earth
  4.   Mars
  5.   Jupiter
  6.   Saturn
  7.   Uranus
  8.   Neptune


Itokasi àtúnṣe