Sístẹ̀mù ìwọ̀n mítà


Sístẹ̀mù ìwọ̀n mítà je iwon sistemu alaayemewa ti orile-ede Fransi koko gba se ni 1791 to si ti di sistemu ìwọ̀n ẹyọ to wopo ti gbogbo awon orile-ede agbaye n lo.

Countries which have officially adopted the metric system. Only three nations have not officially adopted the International System of Units as their primary or sole system of measurement: Burma, Liberia, and the United States.



Itokasi àtúnṣe