Stella Obasanjo (14 November 1945 – 23 October 2005) ni Iyaafin Akoko ile Naijiria lati 1999 titi di ojo iku re ni 23 osu kewa, 2005. Ohun ni iyawo aare totikoja Olusegun Obasanjo.

Stella Obasanjo
Ìyáàfin Àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
29 May, 1999 – 23 October, 2005
AsíwájúFati Lami Abubakar
Arọ́pòTurai Yar'Adua
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí14 November 1945
Esan West, Edo State, Nigeria
Aláìsí23 October 2005(2005-10-23) (ọmọ ọdún 59)
Puerto Banús, Marbella, Spain
(Àwọn) olólùfẹ́Olusegun Obasanjo