Tukur Yusuf Buratai (ojoibi 24 Osu Kokanla 1960) je Igbakeji Ogagun ara Naijiria ati Oga awon Omose Agbogun ile Naijiria lowo,[1] ipo ti Aare Muhammadu Buhari yan si ni Osu Keje 2015.[2] O gba ipo ologun ni 1983, latigba na o ti sise ni ipo orisirisi bi oga, alamojuto ati olukoni.

Tukur Yusuf Buratai
Lt.Gen.Tukur Yusuf Buratai 2018
Ọgá àwọn Ọmọṣẹ́ Agbógun
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
July 2015
AsíwájúLT-Gen. Kenneth Minimah
Commander, Multinational Joint Task Force
In office
May 2014 – July 2015
AsíwájúBrig-Gen. E. Ransome-Kuti
Arọ́pòMaj-Gen. Iliya Abbah
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kọkànlá 1960 (1960-11-24) (ọmọ ọdún 63)
Alma materNigerian Defence Academy
University of Maiduguri
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/service Nigerian Army
Years of service1981 –
RankLieutenant general
CommandsMultinational Joint Task Force
Battles/warsBoko Haram Insurgency War


Itokasi àtúnṣe

  1. "Nigerian Army Chronicle of Command". Nigerian Army. Archived from the original on 21 July 2015. Retrieved 16 September 2015. 
  2. George, Agba. "Major General TY Buratai New Chief Of Army Staff". Retrieved 13 July 2015.