Werner Heisenberg (5 December 1901 – 1 February 1976) je ara Germany to je onimo fisiyiki oniro to se afikun pataki si isise ero atasere ti o si gbajumo fun titenumo opo aidaju fun iro atasere. Bakanna, o tun se afikun pataki si fisiksi inuatomu, iro papa atasere, ati fisiksi eleruku.

Werner Heisenberg
ÌbíWerner Karl Heisenberg
(1901-12-05)5 Oṣù Kejìlá 1901
Würzburg, Germany
Aláìsí1 February 1976(1976-02-01) (ọmọ ọdún 74)
Munich, Germany
Ọmọ orílẹ̀-èdèGermany
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Göttingen
University of Copenhagen
University of Leipzig
University of Berlin
University of St Andrews
University of Munich
Ibi ẹ̀kọ́University of Munich
Doctoral advisorArnold Sommerfeld
Other academic advisorsNiels Bohr
Max Born
Doctoral studentsFelix Bloch
Edward Teller
Rudolph E. Peierls
Reinhard Oehme
Friedwardt Winterberg
Peter Mittelstaedt
Şerban Ţiţeica
Ivan Supek
Erich Bagge
Hermann Arthur Jahn
Raziuddin Siddiqui
Heimo Dolch
Hans Euler
Edwin Gora
Bernhard Kockel
Arnold Siegert
Wang Foh-san
Other notable studentsWilliam Vermillion Houston
Guido Beck
Ugo Fano
Ó gbajúmọ̀ fúnUncertainty Principle
Heisenberg's microscope
Matrix mechanics
Kramers-Heisenberg formula
Heisenberg group
Isospin
InfluencedRobert Döpel
Carl Friedrich von Weizsäcker
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1932)
Max Planck Medal (1933)
Religious stanceLutheran
Notes
He was the father of the neurobiologist Martin Heisenberg and the son of August Heisenberg

Heisenberg, pelu Max Born ati Pascual Jordan, se ilalele apoti nomba fun isise ero atasere ni 1925. Heisenberg gba Ebun Nobel ninu Fisiyiki ni 1932.

Leyin Ogun Agbaye Keji, o di oludari Kaiser Wilhelm Institute for Physics, to yi oruko si Max Planck Institute for Physics. Ohun ni oludari ile-ekose yi titi ti won fi gbe lo si Munich in 1958, nibi ti won ti fe po si, ti wo si tun yi oruko re si Max Planck Institute for Physics and Astrophysics.

Heisenberg je aare German Research Council, alaga Commission for Atomic Physics, alaga Nuclear Physics Working Group, ati aare Alexander von Humboldt Foundation.


Itokasi àtúnṣe