Rajinikanth

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Indian

Shivaji Rao Gaekwad (bìi ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kejìlá Ọdún 1950) wọ́n t́n mọ̀ọ́ sí Rajinikanth, jẹ́ òṣère eré ìtàgé Orílẹ èdè Indian tí ó ń ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ fiimu Tamil. Ó ti kópa nínú eré àwon Bollywood, Telugu, Kannada, Malayalam , Hollywood ati  eré  ìtàgé ní ède Bengali. Ó b`ẹr`ẹ eré ìtàgé ṣíṣe nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ olùdarí  ọk`ọ p`ẹlú ilé iṣẹ́ ọk`ọ wíwà Bangalore. Ní ọdún 1973, ó darapọ mọ́ ilé `ẹkọ Madras Film Institute lati gba oyè diploma nínú eré ìtàgé ṣíṣe[1][1][2][3][4]

Rajinikanth
Ọjọ́ìbíShivaji Rao Gaekwad
12 Oṣù Kejìlá 1950 (1950-12-12) (ọmọ ọdún 73)
Bangalore, Mysore State, India
(now in Karnataka, India)
IbùgbéChennai, Tamil Nadu, India
Orílẹ̀-èdèIndian
Iṣẹ́Film actor, producer
Ìgbà iṣẹ́1975–present
Olólùfẹ́Latha Rajinikanth (1981–present)
Àwọn ọmọ
Àwọn olùbátansee Rajinikanth family tree
Awards Padma Vibhushan (2016)
Padma Bhushan (2000)

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe