René Descartes (ìpè Faransé: ​[ʁəne dekaʁt]; 31 March 1596 – 11 February 1650) (Kiko ni Latin: Renatus Cartesius; oro aponle: "Kartesi" tabi "Cartesian" ni geesi),[2] je amoye ara Fransi, onimo mathimatiki, onimo fisksi, ati olukowe to gbe opo igbesiaye agbalagba re ni orile-ede Hollandi Olominira. Won ti pe ni bi "Baba Imoye Odeoni", beesini opo Imooye apaiwoorun je bi esi si awon iwe to ko, ti won si tun unje gbigbeka momomo doni. Agaga, iwe re Meditations on First Philosophy si je doni iwe pataki ni awon ipin-apa imoye ni awon yunifasiti. Ipa Descartes ninu mathimatiki han kedere; ohun lo seda sistemu ajofonako Kartesi—ungba irisi jeometri laaye lati je gbigbekale ni isedogba aljebra. Ohun lo je sisawin bi baba jeometri alatuwo. Descartes na tun je ikan ninu awon to se bere Ijidide Sayensi.

René Descartes
Rene Dekart
Portrait after Frans Hals, 1648.[1]
OrúkọRené Descartes
Rene Dekart
Ìbí(1596-03-31)Oṣù Kẹta 31, 1596
La Haye en Touraine (titunso di Descartes), Indre-et-Loire, Fransi
AláìsíFebruary 11, 1650(1650-02-11) (ọmọ ọdún 53)
Stockholm, Swidin
ÌgbàÌmòye ọrúndún 17th
AgbègbèÌmòye Apáìwọ̀orùn
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Cartesianism, Rationalism, Foundationalism
Ìjẹlógún ganganMetaphysics, Epistemology, Science, Mathematics
Àròwá pàtàkìCogito ergo sum, method of doubt, Cartesian coordinate system, Cartesian dualism, ontological argument for the existence of God; regarded as a founder of Modern philosophy
Ìtọwọ́bọ̀wé
  1. Russell Shorto. Descartes' Bones. (Doubleday, 2008) p. 218; see also The Louvre, Atlas Database, http://cartelen.louvre.fr
  2. Colie, Rosalie L. (1957). Light and Enlightenment. Cambridge University Press. p. 58.