Roubaix

Àwọn ìlú ní Fránsì

Roubaix (ìpè Faransé: ​[ʀu.bɛ]) jẹ́ atijọ iṣẹ́ ìlú kan ní apá àríwá Fránsì, nítòsí ìlú Tourcoing àti àwọn ààlà pẹ̀lú Bẹ́ljíọ̀m. Agbègbè náà tóbi tó 13.23 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 95,866 nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.

Gbọ̀ngàn Ìlú Roubaix

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe