Orílẹ̀-èdè kan ni ó ń jẹ́ American Samoa. Ètò ìkànìyàn 1995 sọ pé àwọn ènìyàn ibè jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ojójì ó lé mẹ́ta (43, 000). Èdè Gèésì ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba. Ìdá àádọ́rùn-ún nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ibẹ̀ ni ó ń sọ Samoan. Àwọn kan tún ń sọ Tongan àti Tokelau

American Samoa
Amerika Sāmoa / Sāmoa Amelika
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Samoa, Muamua Le Atua"  (Samoan)
"Samoa, Let God Be First"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèThe Star-Spangled Banner, Amerika Samoa
OlúìlúPago Pago1 (de facto), Fagatogo (seat of government)
ilú títóbijùlọ Tafuna
Èdè àlòṣiṣẹ́ English,
Samoan
Orúkọ aráàlú Ará Sàmóà Amẹ́ríkà
Ìjọba Unincorporated territory of the United States
 -  President Barack Obama (D)
 -  Governor Togiola Tulafono (D)
 -  Lieutenant Governor Ipulasi Aitofele Sunia (D)
Aṣòfin Fono
 -  Ilé Aṣòfin Àgbà Senate
 -  Ilé Aṣòfin Kéreré House of Representatives
Unincorporated territory of the United States
 -  Tripartite Convention 1899 
 -  Deed of Cession of Tutuila
1900 
 -  Deed of Cession of Manu'a
1904 
 -  Annexation of Swains Island
1925 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 199 km2 (212th)
76.83 sq mi 
 -  Omi (%) 0
Alábùgbé
 -  2010 census 55,519 (208th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 326/km2 (35th)
914/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2007
 -  Iye lápapọ̀ $537 million (187)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $8,000 (98)
Owóníná US dollar (USD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè Samoa Standard Time (SST) (UTC-11)
Àmìọ̀rọ̀ Internet .as
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +1-684
1 Fagatogo is identified as the seat of government.
Map of American Samoa.ItokasiÀtúnṣe